Billie Jean King (omo idile Moffitt; ojoibi November 22, 1943) je agba tenis tele ara Amerika. O gba awon ife-eye enikan Grand Slam 12, ife-eye Grand Slam awon obinrin enimeji 16, ati ife-eye Grand Slam awon tokunrin-tobinrin 11.

Billie Jean King
Orílẹ̀-èdèUSA
IbùgbéUSA
Ọjọ́ìbíOṣù Kọkànlá 22, 1943 (1943-11-22) (ọmọ ọdún 80)
Long Beach, California
Ìga1.64 m (5 ft 5 in)
Ìgbà tódi oníwọ̀fà1968
Ìgbà tó fẹ̀yìntì1983
Ọwọ́ ìgbáyòRight-handed
Ẹ̀bùn owóUS$1,966,487[1]
Ilé àwọn Akọni1987 (member page)
Ẹnìkan
Iye ìdíje695–155 (81.76%)
Iye ife-ẹ̀yẹ129 (84 during open era)
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 1 (1966, 1967, 1968, 1971, 1972, 1974)
Grand Slam Singles results
Open AustrálíàW (1968)
Open FránsìW (1972)
WimbledonW (1966, 1967, 1968, 1972, 1973, 1975)
Open Amẹ́ríkàW (1967, 1971, 1972, 1974)
Ẹniméjì
Iye ìdíje87–37 (as shown on WTA website)[1]
Grand Slam Doubles results
Open AustrálíàF (1965, 1969)
Open FránsìW (1972)
WimbledonW (1961, 1962, 1965, 1967, 1968, 1970, 1971, 1972, 1973, 1979)
Open Amẹ́ríkàW (1964, 1967, 1974, 1978, 1980)
Àdàpọ̀ Ẹniméjì
Iye ìdíjen/a
Iye ife-ẹ̀yẹ11
Grand Slam Mixed Doubles results
Open AustrálíàW (1968)
Open FránsìW (1967, 1970)
WimbledonW (1967, 1971, 1973, 1974)
Open Amẹ́ríkàW (1967, 1971, 1973, 1976)
Last updated on: February 7, 2008.

Billie Jean King ni oludasile WTA.


Itokasi àtúnṣe

  1. 1.0 1.1 "Women's Tennis Association biography of Billie Jean King". Sonyericssonwtatour.com. Archived from the original on July 5, 2009. Retrieved July 4, 2011.