Boris Becker
Boris Franz Becker (ojoibi 22 November 1967) je agba tenis to ti feyinti to je Eni Ipo 1 Lagbaye tele lati orile-ede Jemani. O gba ife-eye Grand Slam ni emefa bi enikan, eso Wura kan ninu idije enimeji ni Olimpiki, ati eni ti ojo-ori re kerejulo to gba Idije Wimbledon awon okunrin enikan nigba to je omo-odun 17.
Orílẹ̀-èdè | West Germany (1983–1990) Jẹ́mánì (from 1990) |
---|---|
Ibùgbé | Schwyz, Switzerland |
Ọjọ́ìbí | 22 Oṣù Kọkànlá 1967 Leimen, West Germany |
Ìga | 1.90 m (6 ft 3 in) |
Ìgbà tódi oníwọ̀fà | 1984 |
Ìgbà tó fẹ̀yìntì | 30 June 1999 |
Ọwọ́ ìgbáyò | Right-handed (one-handed backhand) |
Ẹ̀bùn owó | $25,080,956 |
Ilé àwọn Akọni | 2003 (member page) |
Ẹnìkan | |
Iye ìdíje | 713–214 (76.91%) |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 49 |
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 1 (28 January 1991) |
Grand Slam Singles results | |
Open Austrálíà | W (1991, 1996) |
Open Fránsì | SF (1987, 1989, 1991) |
Wimbledon | W (1985, 1986, 1989) |
Open Amẹ́ríkà | W (1989) |
Àwọn ìdíje míràn | |
Ìdíje ATP | W (1988, 1992, 1995) |
WCT Finals | W (1988) |
Ìdíje Òlímpíkì | 3R (1992) |
Ẹniméjì | |
Iye ìdíje | 254–136 |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 15 |
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 6 (22 September 1986) |
Grand Slam Doubles results | |
Open Austrálíà | QF (1985) |
Àwọn ìdíje Ẹniméjì míràn | |
Ìdíje Òlímpíkì | Ẹ̀sọ́ Wúrà (1992) |
Àwọn Ìdíje Ẹgbẹ́ Agbáyò | |
Davis Cup | W (1988, 1989) |
Hopman Cup | W (1995) |
Last updated on: January 23, 2012. |
Iye ẹ̀ṣọ́ Olympiki | ||
Men's Tennis | ||
---|---|---|
Wúrà | 1992 Barcelona | Men's doubles |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |