Brunei (pípè /bruːˈnaɪ/), fun onibise gege bi Orile-ede ile Brunei Darussalam tabi Orileabinibi ile Brunei, Ibi Alafia (Àdàkọ:Lang-ms, Jawi: بروني دارالسلام), je orile-ede to budo si eti odo ariwa erekusu ile Borneo, ni Guusuilaorun Asia. Oto si eto odo re pelu Okun Guusu Saina o je yiyipo patapata pelu ipinle Sarawak ni Malaysia, ooto si n pe o je pipinya si apa meji pelu Limbang, to je apa Sarawak.

Negara Brunei Darussalam
State of Brunei, Abode of Peace
بروني دارالسلام
Àsìá
Motto"Always in service with God's guidance"  (translation)
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèAllah Peliharakan Sultan
God Bless the Sultan

Ibùdó ilẹ̀  Brunei  (green) ní ASEAN  (dark grey)  —  [Legend]
Ibùdó ilẹ̀  Brunei  (green)

ASEAN  (dark grey)  —  [Legend]

Olúìlú
(àti ìlú títóbijùlọ)
Bandar Seri Begawan
Èdè àlòṣiṣẹ́ Malay (Bahasa Brunei)[citation needed]
Àwọn èdè dídámọ̀ níbẹ̀ English, Arabic, Indonesian
Orúkọ aráàlú Ará Brunei
Ìjọba Islamic Absolute Monarchy
 -  Sultan Hassanal Bolkiah
 -  Crown Prince Al-Muhtadee Billah
Formation
 -  Sultanate 14th century 
 -  End of
British protectorate
January 1, 1984 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 5,765 km2 (172nd)
2,226 sq mi 
 -  Omi (%) 8.6
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2009 400,000[1] 
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 69.4/km2 (134th)
179.7/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2008
 -  Iye lápapọ̀ $19.716 billion[2] (114th)
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $50,198[2] (5th)
GIO (onípípè) Ìdíye 2008
 -  Àpapọ̀ iye $14.553 billion[2] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $37,053[2] (24th)
HDI (2007) 0.920[3] (high) (30th)
Owóníná Brunei dollar (BND)
Àkókò ilẹ̀àmùrè (UTC+8)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ left
Àmìọ̀rọ̀ Internet .bn
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù +6731
1 Also 080 from East MalaysiaItokasiÀtúnṣe

  1. Department of Economic and Social Affairs Population Division (2009) (.PDF). World Population Prospects, Table A.1. 2008 revision. United Nations. http://www.un.org/esa/population/publications/wpp2008/wpp2008_text_tables.pdf. Retrieved 2009-03-12. 
  2. 2.0 2.1 2.2 2.3 "Brunei". International Monetary Fund. Retrieved 2009-10-01. 
  3. "Human Development Report 2009. Human development index trends: Table G" (PDF). The United Nations. Retrieved 2009-10-05.