Captain Phillips (eré)
Captain Phillips jẹ́ eréAmẹ́ríkà aṣaragágá ọdún 2013 tí Paul Greengrass darí, ti Tom Hanks àti Barkhad Abdi kópa, tí ó da lórí ìgbésíayé ẹnìkan tí ó yè. Eré yìí dá lórí ìtanÌfipá Gba Maersk Alabama tí ó ṣẹlẹ̀ ní ọdún 2009, ìṣẹ̀lẹ̀ tí ó ṣẹlẹ̀ nígbà tí àwọn ajalèlókun ti òkun India tí adarí wọn jẹ́ Abduwali Muse mú oníṣowó ojú omí, Captain Richard Phillips fún pàṣípààrọ̀. Billy Ray ṣe ìfàwòránsọ̀tàn ẹ̀ tí ó dálóríi ìwé A Captain's Duty: Somali Pirates, Navy SEALs, and Dangerous Days at Sea tí Stephan Talty àti Captain Richard Phillips kọ ní ọdún 2010. Scott Rudin, Dana Brunetti àti Michael De Luca ló ṣàgbéjade iṣẹ́ yìí. Wọ́n ṣe àfihàn ẹ̀ New York Film Festival ti ọdún 2013,[1] wọ́n gbejade fún wíwò ní Ojọ́ mọ́kànlá Oṣù kẹsán Odún 2013.[2]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Paul Greengrass film to open New York Film Festival". BBC News. August 1, 2013. Retrieved August 23, 2013.
- ↑ Daily Mail Reporter (April 20, 2012). "Tom Hanks climbs aboard to film Captain Phillips biopic in which he's captured by Somali pirates". Daily Mail (London). http://www.dailymail.co.uk/tvshowbiz/article-2132249/Tom-Hanks-climbs-aboard-film-Captain-Phillips-biopic-hes-captured-Somali-pirates.html. Retrieved July 26, 2013.