Chanda Rubin (ojoibi February 18, 1976) je agba tenis ara Amerika to ti feyinti. O gba ife-eye awon idije WTA Tour enikan meje, ipo re to gajulo ni World No. 6 ni April 8, 1996, leyin igba to de ilajidopin ni Open Australia 1996. Bakanna Rubin de ipo World No. 9 ninu idije enimeji, o gba Open Australia 1996 pelu Arantxa Sánchez Vicario.

Chanda Rubin
Chanda Rubin at the 2010 US Open 01.jpg
Chanda Rubin playing in the U.S. Open Champions Team Tennis September 9, 2010
Orílẹ̀-èdè Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan United States
Ibùgbé Lafayette, Louisiana, US
Ọjọ́ìbí Oṣù Kejì 18, 1976 (1976-02-18) (ọmọ ọdún 44)
Lafayette, Louisiana, U.S.
Ìga 1.68 m (5 ft 6 in)
Ìgbà tódi oníwọ̀fà August 1991
Ọwọ́ ìgbáyò Right-handed (two-handed backhand)
Ẹ̀bùn owó US$4,469,990
Iye ìdíje 399–254
Iye ife-ẹ̀yẹ 7 WTA, 2 ITF
Ipò rẹ̀ gígajùlọ No. 6 (April 8, 1996)
Open Austrálíà SF (1996)
Open Fránsì QF (1995, 2000, 2003)
Wimbledon 4R (2002)
Open Amẹ́ríkà 4R (1992, 1995, 2002)
Iye ìdíje 226–160
Iye ife-ẹ̀yẹ 10 WTA, 3 ITF
Ipò rẹ̀ gígajùlọ No. 9 (April 15, 1996)
Open Austrálíà W (1996)
Open Fránsì SF (2003)
Wimbledon SF (2002)
Open Amẹ́ríkà F (1999)
Last updated on: December 11, 2009.


ItokasiÀtúnṣe