Charles Soludo
Olóṣèlú
(Àtúnjúwe láti Charles Chukwuma Soludo)
Charles Chukwuma Soludo (ojoibi 28 July, 1960) je ojogbon imo isuna, ohun si ni Gomina ati Alaga igbimo awon oludari Ile Ifowopamo Ijoba ile Naijiria lati 29 May, 2004 titi di 29 May, 2009. Ni ojo kesan osu kokanla odun 2021, Soludo to n soju egbe All Progressives Grande Alliance ni won kede gege bi olubori ninu ibo gomina ipinle Anambra ni odun 2021, ti o si bori awon to sunmo re lati egbe PDP ati APC, Valentine Ozigbo ati Emmanuel Nnamdi Uba.
Charles Chukwuma Soludo | |
---|---|
Gomina Ile Ifowopamo Ijoba ile Naijiria | |
In office May 29, 2004 – May 29, 2009 | |
Ààrẹ | Olusegun Obasanjo, then Umaru Yar'Adua |
Asíwájú | J. O. Sanusi |
Arọ́pò | S. L. Aminu Sanusi |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 28 July 1960 Aguata LGA, Anambra State |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Nonye |
Àwọn ọmọ | Four |
Occupation | Economics Professor |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |