Dice Ailes
Shasha Damilola Alesh tí orúkọ ìnagije rẹ̀ ń jẹ́ Dice Ailes, jé akọrin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, akọrinkalẹ̀, àti rápà. Ní oṣù keje, ọdún 2014, ó tẹwọ́ bòwé pẹ̀lú Chocolate City.[1] Wọ́n yàn án fún Rookie of the Year ní The Headies 2016.[2][3] Ní ọdún 2016, orin rẹ̀ TooXclusive ṣe àfihàn orin rè, tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Miracle, ó sì wọ ipò kẹta nínú àwọn orin mẹ́wàá tó dára jù lọ fún oṣù kẹwàá.[4] Ní ọdún 2017, tooXclusive dárúkọ rẹ̀ lára àwọn olórin tó yẹ kí a mọ̀.[5]
Dice Ailes | |
---|---|
Ailes showing his Gold slugs | |
Ọjọ́ìbí | Shasha Damilola Alesh 1 Oṣù Kẹjọ 1996 |
Orílẹ̀-èdè | Nigeian- Canadian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | York University |
Iṣẹ́ | Singer, songwriter, rapper |
Ìgbà iṣẹ́ | 2014–present |
Musical career | |
Irú orin | Pop, Afro pop, Afro hip-hop |
Associated acts | |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀ àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeOrílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni ó ti kékọ̀ọ́ girama, ní ilé-ìwé girama Lagooz, ó sì tún kẹ́kọ̀ọ́ ní Republic of Benin, àti Ghana kí ó tó kó lọ Canada níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ ní York University. Ní ilé-ìwé gíga yìí ni ó ti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ orin kíkọ kí ó tó padà sí Nàìjíríà lẹ́yìn tí ó tẹwọ́ bòwé pẹ̀lú Chocolate City ní ọdún 2014.[6]
Iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeÓ bẹ̀rẹ̀ orin kíkọ nígbà tí ó darapọ̀ mọ́ àwọn ẹgbẹ́ akọrin kan, pẹ̀lú Hyce- age, coker, Millie àti Reihnard nígbà tí ó wà nínú ẹgbẹ́ náà.[7] Ó di gbajúmọ̀ ní ọdún 2016, nígbà tí ó kọ orin "Miracle" pẹ̀lú Lil kesh.[8][9]
Ní ọjọ́ kọkànlélógún, oṣù kejìlá, ọdún 2016, Dice Ailes kọrin pẹ̀lú WSTRN, Krept and Konan, Migos àti Lil kesh ní "Beat FM lọ́jọ́ ayẹyẹ kérésì" ní ọdún 2016 ní Ìpínlẹ̀ Èkó.[10]
Àtòjọ àwọn orin rẹ̀
àtúnṣeOrin àdákọ
àtúnṣeYear | Title | Album |
---|---|---|
2014 | "Fantasy" | Non-album single |
"Telephone" | ||
2015 | "Machinery" | |
2016 | "Miracle" | |
2017 | "Ella" | |
2017 | "Otedola" | |
2018 | "mr biggs" | |
2018 | "Dicey" | |
2018 | "Enough" | |
2019 | "Alakori"[11](feat. Falz)"Ginika" | |
2020 | "Pim Pim" (feat Olamide)[12] |
Year | Title | Album |
---|---|---|
2015 | "Awon Temi"
(Loose Kaynon feat. Dice Ailes & Koker) |
The Gemini Project[13][14] |
2016 | "Brooklyn"
(Ice Prince feat. Dice Ailes) |
Jos to the World |
2017 | "Olohungbo"
(Masterkraft feat. Ceeza, YCEE & Dice Ailes) |
Non-album single |
"No Favors"[15]
(Yung6ix feat. Dice Ailes & Mr. Jollof) | ||
2017 | "Your Father"
(M.I Abaga feat. Dice Ailes) |
Rendezvous |
2019 | "Que Cera”
(Vision DJ feat. Dice Ailes, Kwesi Arthur, Medikal) |
Compilation singles
àtúnṣeYear | Title | Album |
---|---|---|
2015 | "Drank"
(DJ Lambo, Milli, Dice Ailes) |
TICBN |
"Oh No No"
(Dice Ailes) |
Compilation albums
àtúnṣeYear | Title | Released Date |
---|---|---|
2015 | The Indestructible Choc Boi Nation | 30 April 2015 |
Cover
àtúnṣeYear | Artist | Title |
---|---|---|
2016 | MI & Dice Ailes | "Controlla (refix)"[16] |
Àtòjọ àmì-ẹ̀yè tó gbà
àtúnṣeYear | Event | Prize | Recipient | Result |
---|---|---|---|---|
2015 | tooXclusive Awards | Best New Artiste[17] | Himself|style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé[18] | |
2016 | The Headies | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | ||
2018 | style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé[19] |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Dice Ailes Joins Chocolate City". P.M. News. 11 July 2014. Retrieved 27 April 2017.
- ↑ "Mayorkun Wins 'Rookie of the Year' Award at The Headies 2016". BellaNaija. Retrieved 27 April 2017.
- ↑ "Mayorkun, Terry Apala or Dice Ailes: Who will win the Headies 2016 Rookie of the Year award?". Nigerian Entertainment Today. 19 December 2016. Retrieved 27 April 2017.
- ↑ "Top 10 Songs for the Month Of October". WetinHappen Magazine. 7 November 2016. Archived from the original on 11 September 2018. Retrieved 27 April 2017.
- ↑ "TooXclusive's Artistes To Watch in 2017!!!". tooXclusive. Archived from the original on 15 June 2017. Retrieved 19 May 2017.
- ↑ "Chocolate City star Dice Ailes features Lil Kesh in new single 'Miracle' – Vanguard News". Vanguard. 10 October 2016. Retrieved 27 April 2017.
- ↑ "Artiste of the week: Choc Boy, Diles Ailes – Tribune". Nigerian Tribune. 12 May 2017. Retrieved 19 May 2017.
- ↑ Akan, Joey. "Dice Ailes will be a star with Miracle". Pluse Nigeria. Archived from the original on 29 April 2017. Retrieved 27 April 2017.
- ↑ "Rising act, Millywine teams up with Dice Ailes on 'Run Up'". Vanguard Newspaper. 28 June 2020. Retrieved 19 September 2020.
- ↑ Solanke, Abiola. "Migos: Hip hop group party with Nigerian teens at Beat FM Xmas concert". Pulse Nigeria. Archived from the original on 10 May 2017. Retrieved 29 April 2017.
- ↑ "Listen: Falz And Dice Ailes Release New Catchy Tune "Alakori"". The Guardian Nigeria News – Nigeria and World News. 8 June 2019. Archived from the original on 9 June 2019. Retrieved 9 June 2019.
- ↑ "Dice Ailes features Olamide on 'Pim Pim'". P.M News. 28 March 2020. Retrieved 19 September 2020.
- ↑ "Loose Kaynon – The Gemini Project". cloud 9. Archived from the original on 27 March 2016. Retrieved 9 May 2017.
- ↑ Base, MTV (12 January 2016). "News : loose kaynon releases "The Gemini Project"". MTV Base. Retrieved 9 May 2017.
- ↑ "Yung6ix ft. Dice Ailes & Mr. Jollof – No Favors". 360nobs. Archived from the original on 9 May 2017. Retrieved 10 May 2017.
- ↑ Solanke, Abiola. "New Music: M.I Abaga, Dice Ailes – "Controlla" (refix)". Pulse Nigeria. Archived from the original on 7 June 2016. Retrieved 29 April 2017.
- ↑ "tooXclusive Awards 2015 Nominees List". tooXclusive. Retrieved 9 May 2017.
- ↑ "tooXclusive AWARDS 2015 – WINNERS!". tooXclusive. Retrieved 9 May 2017.
- ↑ Ohunyon, Ehis. "Wizkid, Davido, Simi and Mayorkun are among the big winners at the 12th edition of the Headies Music Awards.". Archived from the original on 4 July 2018. https://web.archive.org/web/20180704204722/https://www.pulse.ng/entertainment/music/headies-2018-winners-list-id8339846.html.
Shasha Damilola Alesh dara julọ mọ nipasẹ orukọ ipele rẹ kú Ales,jẹ akọrin olorin ọmọ Naijiria kan, akọrin-akọrin ati olorin kan.Ni Oṣu Keje 2014, o fowo si akọsilẹ kan pẹlu Chocolate Ilu.[1] O pe fun Rookie ti ọdun ni pẹtẹlẹ pari ti ọdun 2016.[2] [3] Ni ọdun 2016, TooXclusive rẹ tun wa ni ipo aṣeyọri "Iyanu lori atokọ ti "Awọn orin 10 Top fun oṣu Oṣu Kẹwa". [4] Ni 2017, tooXclusive ti a npè ni bi "ọkan ninu awọn olorin ti o nilo lati mọ. [5]
Jabọ A kú kùnà Gbogbo ìgbà ló máa ń yẹ àwọn odi rẹ̀ wò Bi Shsha Damilola Alesh 1 August 1996 (ọjọ-ori 25) Orilẹ-ede Nigeian- Canada Alma Yunifasiti York Iyalẹnu olorin, akọrin Awọn ọdun ṣiṣẹ 2014–bayi Irinse orin Awon Agbejade, Afro agbejade, ibadi-akọrin Ni kutukutu igbesi aye ati ẹkọ Iṣẹ Igbadun Awọn ẹbun ati yiyan Wo tun Awọn itọkasi Awọn ọna asopọ ita Ni oṣu to kọja 7 sẹyin nipasẹ Kkbshow