Elizabeth Adekogbe
ọmọnìyàn
ẹ̀yàabo Àtúnṣe
country of citizenshipNàìjíríà Àtúnṣe
name in native languageElisabeth Adekogbe Àtúnṣe
orúkọ àfúnniElizabeth Àtúnṣe
orúkọ ìdíléAdékọ̀gbẹ́ Àtúnṣe
ọjó ìbí1919 Àtúnṣe
ìlú ìbíÌbàdàn Àtúnṣe
ọjó ikú1968 Àtúnṣe
spouseAdékọ̀gbẹ́ Àtúnṣe
native languageÈdè Yorùbá Àtúnṣe
languages spoken, written or signedgẹ̀ẹ́sì, Nigerian Pidgin Àtúnṣe
writing languagegẹ̀ẹ́sì Àtúnṣe
iṣẹ́ oòjọ́ rẹ̀activist, olóṣèlú, civil service Àtúnṣe
position heldtribal chief Àtúnṣe
kẹ́ẹ̀kọ́ níYaba College of Technology, St Agnes Catholic High School Àtúnṣe
honorific prefixtribal chief Àtúnṣe
member of political partyAction Group Àtúnṣe
ethnic groupÌran Yorùbá Àtúnṣe
eye colorbrown Àtúnṣe
hair colorIrun dúdú Àtúnṣe
personal pronounL484 Àtúnṣe

Oloye Elizabeth Adekoge(1919 - 1968)[1] jé olósèlú, ajafun ètó obinrin àti ajafun ominira Nàìjíríà nígbà ayé rè. Òun ní adari ajo women Council ti Nàìjirià. Ní odun 1959, ajo náà darapo pèlú Women's improvement league láti di egbé National Council of women societies,[2] egbé tí óún jà fitafita fún ètó obínrin ní Nàìjíríà.

Àárò ayé àti Èkó rè

àtúnṣe

A bí Adegoke sínú idile oba Ajaloorun ti Ijebu-Ife ní odun 1919. O kàwé ní St Agnes Catholic Training School àti ní College of Technology ti Yaba. Ó padà di osise ìjoba

Ipa rè nínú oselu

àtúnṣe

Ni odun 1952, Adekogbe àti awon obinrin merinla miran dá egbe women's movement kale ní ìlú Ibadan, ète àti erogba egbé náà ni fifi òpòlopò omobinrin sile ìwé, fifi awon obinrin sípò ase àti didin iye owo orí sisan kù.[3] O sisé pèlú àwon eniyan bi Funmilayo Ransome-Kuti láti ja fún ètó omobinrin.

Ìdílé rè

àtúnṣe

Elizabeth Adekogbe fé Alademerin Akija Adekogbe, ní odun 1946, àwon méjèjì kó lo sí Ibadan, ibè ni oko rè ti sise tita cocoa ní ilé-isé kan ní ibadan, tí Elizabeth sì jé adari ilé-ìwé primari Saint James ti ìlú Ibadan. Gegebi Oloye ní ilé Yoruba, Elizabeth lo je ipo Ìyálájé ti Ikija.[4]

Ikú rè

àtúnṣe

Elizabeth Adegoke di ologbe ní odun 1968.[5]

Àwon ìtókasí

àtúnṣe
  1. "Maitron". Maitron (in Èdè Faransé). Retrieved 2022-05-28. 
  2. "Home". NCWSNigeria. 2021-03-15. Archived from the original on 2022-05-25. Retrieved 2022-05-28. 
  3. "Elizabeth Adekogbe and the Women’s Movement of Nigeria". The Republic. 2022-05-12. Retrieved 2022-05-28. 
  4. "Prabook". prabook.com. Retrieved 2022-05-28. 
  5. "Elizabeth Adekogbe" Check |url= value (help). Hyperleap. 1951-10-23. Retrieved 2022-05-28. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]