Fatoumata Coulibaly jẹ oṣere fiimu ara ilu Málì adari, akọroyin, ati ajafẹtọ ẹtọ awọn obinrin, ni pataki julo ko gba di da abe fun awon omobirin.

Fatoumata Coulibaly, 2017

Igbesi aye ibẹrẹ àtúnṣe

Fatoumata Coulibaly wa lati ebi awon olorin, iya-iya e Bazeko Traore je olorin lati apa Sikasso, ibi ti Coulibaly ti wa.[1]

Coulibaly koko sise gegebi akoroyin redio ati olukede ni Mali, ki o to ri imoran fun ere kan, lehin ti o ri imoran na olori oludari Ousmane Sow, Sow so fun pe ki olo ko kale gege bi iwe fiimu, Cheik Oumar Sissoko na so nkan kana fun.[2]

Coulibaly kọkọ fa ifojusi kariaye pẹlu ipa rẹ ninu fiimu 1997 N'Golo dit Papa. [3]

Coulibaly ko ipa iwaju ninu fiimu odun 2004 kan ti akole re je Moolaade, omo ilu Sẹ̀nẹ̀gàl kan ni o ko ere na, Ousmane Sembene lo dari e. Coulibaly ko ipa Collé Gallo Ardo Sy, iyawo keji ninu meta ti oko e fe, ni abule kan ni Bùrkínà Fasò, o man fii agbara idan ti Moolaadé ni lati fi ko awon omo obinrin yo ninu idabe.[4] Coulibaly na je okan lara awon omo obinrin ti won dabe fun.[5] Roger Robert fun ere na ni irawo merin ninu merin, o ni fun ohun ere ti odara ju lo ni Cannes ti odun 2004 ni ere na, o ni ere na ni agbara ti o po, ati pe oni awon nkan ti o pani lerin ninu, aworan e si dara gidi gan, ko da orewa.[6] Coulibaly gba ami eye osere ti odara ju lo fun ipa e gege bi Collé ni ami eye Cinemanila ni odun 2005.[7] Ere na ko ipa ti o ni anfani gidi nipase dida imoye kale fun idabe(FMG) Coulibaly ko ti dawo duro nipa ki oma polongo fun awo eyan nipa ewu ti on be ninu idabe fun awon obirin[8]Won ko ipolongo re sinu ere oni iroyin kan ti won pe akole e ni Africa on the Move: The Power of Song o jade ni odun 2010.[9][10]

Coulibaly ti han ni ọpọlọpọ awọn fiimu, jara tẹlifisiọnu ati awọn ere.

Ni odun 2016, Coulibaly sise pelu Office de radiodiffusion télévision du Mali. (Ile ise ti o man gbe ero telifisonu jade ni Mali)[11]

Filmography àtúnṣe

  • Guimba the Tyrant (1995)
  • N'Golo dit Papa (1997)
  • Aphrodite, the Garden of the Perfumes (1998)
  • Moolaadé (2004), actress
  • Africa on the Move: The Power of the Song (2010)
  • Tourbillon à Bamako (2012)

Awọn itọkasi àtúnṣe

  1. "Mali : Fatoumata Coulibaly: journaliste à l’Ortm, comédienne et réalisatrice de films". maliactu.net. 26 March 2016. Retrieved 9 November 2017. 
  2. "Mali : Fatoumata Coulibaly: journaliste à l’Ortm, comédienne et réalisatrice de films". maliactu.net. 26 March 2016. Retrieved 9 November 2017. 
  3. Janis L. Pallister; Ruth A. Hottell (2005). Francophone Women Film Directors: A Guide. Fairleigh Dickinson Univ Press. p. 24. ISBN 978-0-8386-4046-3. https://books.google.com/books?id=P15tyiOSRz0C&pg=PA24. Retrieved 9 November 2017. 
  4. "African Cinema this SineKultura 2012 – SineBuano.com". sinebuano.com. Archived from the original on 9 November 2017. Retrieved 9 November 2017.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. "A Call to Protect Women and Girls Against a Mutilating Practice". www.wg-usa.org. Archived from the original on 2018-06-16. Retrieved 2018-02-24. 
  6. Ebert, Roger. "Moolaade Movie Review & Film Summary (2007) - Roger Ebert". www.rogerebert.com. Retrieved 9 November 2017. 
  7. "African Cinema this SineKultura 2012 – SineBuano.com". sinebuano.com. Archived from the original on 9 November 2017. Retrieved 9 November 2017.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  8. Worldcrunch. "Facing The Scourge Of Female Genital Mutilation In Africa". worldcrunch.com. Retrieved 9 November 2017. 
  9. "The Power of Song: Africa on the Move". Films Media Group (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2018-02-24. 
  10. Fakoly, Tiken Jah; MacDonald, Ann-Marie; Philibert, Michel; Langlois, Sophie; Josselin, Marie-Laure; Konan, Venance; Coulibaly, Fatoumata; Société Radio-Canada (Firme) (2010). Africa on the Move: The Power of Song (Part 2 of 4). https://apps.uqo.ca/LoginSigparb/LoginPourRessources.aspx?url=http://curio.ca/en/video/africa-on-the-move-the-power-of-song-part-2-of-4-2795/. 
  11. "Mali : Fatoumata Coulibaly: journaliste à l’Ortm, comédienne et réalisatrice de films". maliactu.net. 26 March 2016. Retrieved 9 November 2017.