Fatoumata Diawara
Fatoumata Diawara (tí wọ́n bí ní ọdún un 1982 ní Ivory Coast) jẹ́ òṣèré, olórin àti akọ-orin, tí a ti yàn lọ́pọ̀lọpọ̀ ìgbà fún àmì-ẹ̀yẹ Grammy Award. Ó wá láti orílẹ̀-èdè Málì. Wọ́n fi orúkọ rẹ̀ sílẹ̀ lẹ́ẹ̀mejì fún Grammy Award titi ogótalélọ́kan fún Awo orin agbaye ti o da ju fún àwo orin rẹ̀ Fenfo àti fún orin ijó tí ó dára jù nípasẹ̀, Ultimatum eléyìí tí Disclosure gbà lálejò lórí orin náà [1]
Fatoumata Diawara | |
---|---|
Diawara, August 2012 | |
Background information | |
Ọjọ́ìbí | 1982 (ọmọ ọdún 41–42) Ivory Coast |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Mali |
Irú orin | |
Occupation(s) |
|
Labels | |
Website | fatoumatadiawara.com |
Igbesiaye
àtúnṣeIlu Ivory Coast ni own bi Diawara si fun awon obi ti o wa lati Mali. Ni asiko odo e, won mu pada losi Bamako ni Mali, ki o lo ma gbe loda anti re. Ni igba ti o pe omo odun mejidinlogun o ko lo si ilu France lati lo ma se ise osere. O padi si Mali fun igba die fun ipa kan ninu ere, sugbon o pada si Paris lesekese, nitori ko fe ki won fipa mu lo si ile oko.
Ni gba ti oya, Diawara pada mu jita, osi bere si ni ko awon orin titi e, awon orin ti o ni awon asa Wassoulou ti apa guusu Mali, pelu awon ipa agbaye ninu orin e.
Fiimu ati ere itage
àtúnṣeLehin igba ti o ko lo si France, o ko ipa ninu ere Cheik Oumar Sissoko ti o se ni odun 1999 ti akori re je Genesis, Dani Kouyate, ni odun 2001 o ko ipa ninu ere Sia, le rêve du python ati egbe ere itage ti Royal de Luxe. O tun ko ipa ninu ere olorin ti akole re je Kirikou et Karaba.[2]
Nigbakanna bi o sen korin, ni o n se ere ori itage na, pelu orisirisi ipa pelu orisirisi ere otun ko orin fun orisiris ere bi Timbuktu, ere yi gba Ami eye César meje ati yiyan lati owo Academy Award ni odun 2014[3]
O je gbajumo fun ohun aladun[4] Ede Bambara ni oma fin korin, ede yi je ede abinibi ti Mali, orin e sima da lori igbani niyanju bi asa titi awon Wassoulou[5] DIawara ti korin pelu awon omo orile ede Mali ati awon olorin agbaye bi Cheik Tidiane Seck, Oumou Sangare[6], AfroCubism,[7] Dee Dee Bridgewater ,[8] ati the Orchestre Poly Rythmo de Cotonou.[9] Awo orin e Kanou jade ni ojo kesan osu karun odun 2011. Ohun lo ko gbogbo orin ti owa ni inu awo na.[10] Awon orin e alakoko ti o fi lole, Fatou lati owo World Circuit records ni osu kesan odun 2011[11] Nonesuch Records fi Kanou EP kale ni ori ayelujara ni Àríwá Amẹ́ríkà ni ojo ketadinlogbon osu kesan odun 2011 won si fi awon orin Fatou ni ojo kejidinlogbon osu kejo odun 2012.[12]
Ni osu kesan odun 2012, Diawara kopa ninu ipolongo ti akori e je "30 Songs / 30 Days" lati fi fun Half the Sky ni ati leyin, eleyi je ise agbase media to po ti o waye nipase iwe Sheryl WuDunn ati Nicholas Kristof[13] Nigbakan na ni osu kesan odun 2012, o wa lori eto African Express Train pelu awo eyan bi Damon Albarn, Rokia Traoré, Baaba Maal, Amadou & Mariam, Nicolas Jaar ati awon Noisettes, ati bebe lo. Eto na gba alejo awon eyan ẹgbaaji o le ẹdẹgbẹta ni Kings Cross ibi ti Fatoumata ti korin pelu Paul McCartney.[14]
Diawara ti lo awon odun yi lati fe sere kakiri agbaye,[15]ni Ajodun Glastonbury titi odun 2013, Fatoumata ko orin fun awon eledi geesi, ere ojo na dun yato.[16] Yato fun awon ere orin Europe won ti pe ki o wa korin ni Gúúsù Amẹ́ríkà, Ásíà ati Austrálíà,[17]oti lo si ilu Amẹ́ríkà lopolopo igba, ni odun 2013 o sere fun won ni Clinton Global Initiative legbe The Roots ni ilu New York [18] Lati arin odun 2014 ni oti ba opolopo awon osere korin, awon osere bi Roberto Fonseca ti won ti jo se opolopo orin kiko ori itage ati awo orin ti ori itage ti akori e je At Home - Live in Marciac. Ni odun 2014 o korin pelu Mayra Andrade ati Omara Portuondo. Ni osu keji odun 2015, o se orin kiko ti ori itage gegebi olorin agbeya fun igba akoko ni Mali, ni Festival Sur Le Niger[19]ni Segou, nibi ti oti korin pelu ore e ti ojo tope ati ani ti on wo awo kose e, Oumou sangare, Bassekou Kouyate ati opolopo awon olorin ti o wa lati ilu Mali.
Ninu awon ori e, Diawara man soro nipa wahala to wa ninu isilo, inilo fun owo fun arawa, wahala ti awon obinrin ile africa man se; igbe aye labe ofin esin ati iwa didabe fun omo obinrin.[20] Ninu orin e kan "Mali-ko (Peace/La Paix)" orin yi gun fun iseju meje, ere orin e na soro nipa isegun ariwa Mali, o so pe ki a pa ina ikorira ti a ni si awon ara Tuareg, ti o so pe awon lo fa ilolu won.[21] Diawara so wipe ohun nilo lati pariwo pelu orin yi pe ki ilu Mali ji, won ti padanu ara won, ati ise won ati ibi ti won ti wa.[22]
Awon asayan ere
àtúnṣe- 1996: Taafe Fanga by Adama Drabo
- 1999: La Genèse by Cheick Oumar Sissoko: Dina
- 2002: Sia, le rêve du python by Dani Kouyaté: Sia
- 2008: Il va pleuvoir sur Conakry, by Cheick Fantamady Camara: Siré
- 2010: Encourage, by Eleonora Campanella
- 2010: Ni brune ni blonde, by Abderrahmane Sissako
- 2011: Les Contes de la Nuit, by Michel Ocelot (voice)
- 2013: The Africa Express, by Renaud Barret and Florent de La Tulle: Herself
- 2014: Timbuktu (Le chagrin des oiseaux), by Abderrahmane Sissako
- 2015: Morbayassa, by Cheick Fantamady Camara: Bella
- 2016: Mali Blues, by Lutz Gregor: Herself
- 2019: Yao, by Philippe Godeau: Gloria
Itage
àtúnṣe- 1998: Antigone by Sophocles; adapted by Jean-Louis Sagot Duvauroux, production Sotiguy Kouyaté
- 2002–2008: Royal de Luxe; creator Jean-Luc Courcoult
- 2007–2008: Kirikou et Karaba: Karaba
Aworan iwoye
àtúnṣeAwọn awo-orin
àtúnṣe- 2011: Fatou (World Circuit/Nonesuch)
- 2015: At Home - Live in Marciac, Fatoumata Diawara & Roberto Fonseca (Jazz Village)
- 2018: Fenfo (Something To Say) (Wagram Music/Shanachie Records)
Orin Kekeke ati awọn EP
àtúnṣe- 2011: Kanou EP (World Circuit/Nonesuch)
Awọn ifowosowopo
àtúnṣe- 2009: Ifihan ninu awo orin Léman nipasẹ Blick Bassy
- 2010: Ajọ-kikọ ati ifihan ninu awo-orin Debademba nipasẹ Debademba
- 2010: Ifihan ninu The Fojuinu Project nipasẹ Herbie Hancock
- 2010: Ifihan ninu awo-orin Jamm nipasẹ Cheikh Loô
- 2010: Ṣe ifihan ninu orin “N’fletoun” lati inu awo-orin Djekpa La Iwọ nipasẹ Dobet Gnahoré
- 2011: Ifihan ninu orin “C’est lui ou c’est moi” lati awo-orin Cotonou Club nipasẹ Orchester Poly-Rythmo de Cotonou
- 2012: Ifihan ninu Rocket Oje & Oṣupa ( Otitọ Jon's - Iwe-orin)
- 2012: Ifihan ninu orin "Bibissa" lati awo-orin Yo nipasẹ Roberto Fonseca
- 2012: Ifihan ninu orin “Nothin 'Can Fi Ya” lati awo-orin naa Brave Man In The Universe nipasẹ Bobby Womack
- 2013: Ifihan ninu orin “Surma” lati awo-orin Sketches ti Ethiopia nipasẹ Mulatu Astatke
- 2014: Ajọ-kikọ ati ifihan ninu orin "Timbuktu Fasso" lati orin orin Timbuktu nipasẹ Amine Bouhafa
- 2014: Ifihan ninu orin “Gbogbo rẹ n wa papọ” nipasẹ Walter Hus lati ohun orin lati ṣe ẹya fiimu N - The Madness of Reason nipasẹ Peter Krüger
- 2018: Ifihan ninu orin “Ultimatum” nipasẹ Ifihan
- 2019: Ifihan ninu orin “Cameroon” nipasẹ Bonaparte (akorin)
- 2020: Ifihan ninu orin “ Désolé ” nipasẹ Gorillaz
- 2020: Ifihan ninu orin " Douha (Mali Mali) " nipasẹ Ifihan
Pẹlu Les Balayeurs du désert
àtúnṣeNipasẹ ajọṣepọ pẹlu Royal de Luxe ; ọpọlọpọ awọn orin naa ni a ti ṣiṣẹ bi ibamu ni awọn iṣe ita Royal de Luxe 'awọn omiran marionettes' jakejado agbaye.
- 2005: Jules Verne Impact by Les Balayeurs du désert (apast – Album) (Y Danse, Hamleti...)
- 2007: La Pequeña by Les Balayeurs du désert (Atelier de l'événement – Album) (with an early version of Salimata)
Awọn itọkasi
àtúnṣe- ↑ "61st GRAMMY Awards: Full Nominees & Winners List". GRAMMY.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-12-07. Retrieved 2020-02-24.
- ↑ Chabasseur, Eglantine. "Fatoumata Diawara Reinvented" Archived 2011-12-06 at the Wayback Machine., RFI musique, April 8, 2009, accessed June 8, 2011.
- ↑ Keslassy, Elsa (2015-02-20). "'Timbuktu' Sweeps France's Cesar Awards". Variety (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-02-24.
- ↑ Forgan, Kat. “Staff Brenda Bilili”. “Songlines”, July 2011, p.104-105.
- ↑ "Singer and Guitarist Fatoumata Diawara to Perform in New York City | World Music Central.org" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-03-12.
- ↑ Cummings, Tim. "Oumou Sangare, Barbican Hall, London", The Independent, April 28, 2009, accessed June 8, 2011.
- ↑ Phillips, Glyn. "AfroCubism", WorldMusic.co.uk, accessed June 8, 2011.
- ↑ Stoudmann, Elisabeth. "Fatoumata Diawara: Nouvelle deesse malienne". Vibrations, June 2011
- ↑ Denselow, Robin. "Orchestre Poly-Rythmo: Cotonou Club", The Guardian, March 24, 2011, accessed June 8, 2011.
- ↑ McNicoll, Tracy (2013-02-05). "Fatoumata Diawara: A Malian Singer Fights Back Against Islamists". Newsweek (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-03-12.
- ↑ Denselow, Robin (September 15, 2011). "Fatoumata Diawara: Fatou – review". The Guardian (London). https://www.theguardian.com/music/2011/sep/15/fatoumata-diawara-fatou-review. Retrieved 25 September 2011.
- ↑ "Fatoumata Diawara". Nonesuch.com. Archived from the original on 2013-09-14. Retrieved 2013-09-04. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Archived copy". Archived from the original on 2012-10-14. Retrieved 2012-08-31. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Jonze, Tim. "The African journey is over – but what an amazing ride". The Guardian. Retrieved 2013-11-18.
- ↑ "Past Dates". Bands in Town. Retrieved 2013-11-18.
- ↑ Morgan, Andy. "Mali hits Glastonbury: Rokia Traoré, Fatoumata Diawara and more". The Guardian. Retrieved 2013-11-18.
- ↑ "Past Events". Bands in Town. Retrieved 2013-11-18.
- ↑ "2013 Clinton Global Citizen Awards". Clinton Global Initiative. Archived from the original on 2013-09-27. Retrieved 2013-11-18. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Pryor, Tom. "Field Report: Festival Sur Le Niger 2015". Afropop Worldwide. Archived from the original on 2016-03-04. Retrieved 2015-11-11.
- ↑ "Singer and Guitarist Fatoumata Diawara to Perform in New York City | World Music Central.org" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-03-12.
- ↑ McNicoll, Tracy (2013-02-05). "Fatoumata Diawara: A Malian Singer Fights Back Against Islamists". Newsweek (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-03-12.
- ↑ McNicoll, Tracy (2013-02-05). "Fatoumata Diawara: A Malian Singer Fights Back Against Islamists". Newsweek (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-03-12.
Awọn ọna asopọ ita
àtúnṣe- [http:// Official website]
- BBC Radio 3 - World Routes, November 13, 2010, accessed June 8, 2011.
- "Field Report: Festival Sur le Niger 2015" by Tom Pryor Archived 2016-03-04 at the Wayback Machine., accessed November 11, 2015.
- Chabasseur, Eglantine. "Fatoumata Diawara Reinvented", RFI musique, April 8, 2009, accessed June 8, 2011.
- Cummings, Tim. “Oumou Sangare, Barbican Hall, London”, The Independent, April 28, 2009, accessed June 8, 2011.
- Denselow, Robin. "Orchestre Poly-Rythmo: Cotonou Club", The Guardian, March 24, 2011, accessed June 8, 2011.
- Forgan, Kat. "Staff Brenda Bilili". Songlines, July 2011, pp. 104–105.
- Phillips, Glyn. "AfroCubism", WorldMusic.co.uk, accessed June 8, 2011.