Frank Ugochukwu Edwards (ti a bi ní 22 July 1989) jé olórin Nigerian,alágbèjáde, ẹrọ adàpọ̀ mọ́ ohun, olórin iyín ati wipe o máa kọ orin ọmọ ilu Enugu.[1] Oun ni oludasile ati eniti o ni the record label Rocktown Records, ti o je ile gbigba orin silẹ fún àwọn Olórin bi Edwards fún ara e, Gil Joe, King BAS, Nkay, Dudu ati bebe lo. Ilu Eko, ni orile-ede Nigeria, lo n gbe.

  1. "Frank Edwards biography". music.naij.com. Archived from the original on 14 July 2014. Retrieved 5 June 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
Frank Edwards
Background information
Orúkọ àbísọFrank Ugochukwu Edwards
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíiFrankRichboy
Ọjọ́ìbí22 Oṣù Keje 1989 (1989-07-22) (ọmọ ọdún 35)
Ìbẹ̀rẹ̀Enugu State, Nigeria
Irú orin
Occupation(s)
Instruments
  • Vocals
  • piano
  • drums
  • guitar
Years active2007–present
LabelsRocktown
Websitefrankincense.world