Gùyánà Fránsì
Gwiyánì faransé[2] (Faransé: Guyane française, ìpè Faransé: [ɡɥijan fʁɑ̃sɛz]; Guyane ní èdè àjùmọ̀lò) jẹ́ ìpínlẹ̀ kan lára ilẹ̀ Fránsì ní apá àríwá Gúúsù Amẹ́ríkà. Gwiyánì faransé budo lari Sùrìnámù ní ìwọ oòrùn àti Bràsíl ní gúúsù àti ìlà oòrùn.
Gwiyánì faransé Guyane | |||
---|---|---|---|
| |||
Country | France | ||
Prefecture | Cayenne | ||
Departments | 1 | ||
Government | |||
• President | Antoine Karam (PSG) | ||
Area | |||
• Total | 83,534 km2 (32,253 sq mi) | ||
Population (2008) | |||
• Total | 221,500 | ||
• Density | 2.7/km2 (6.9/sq mi) | ||
Time zone | UTC-3 (UTC-3) | ||
GDP/ Nominal | € 2.3 billion (2006)[1] | ||
GDP per capita | € 11,690 (2006)[1] | ||
NUTS Region | FR9 | ||
Website | www.ctguyane.fr |
Ká mọ́ ṣe àṣìṣe rẹ̀ mọ́ Gùyánà tàbí Guinea Faransé.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 "GDP per inhabitant in 2006 ranged from 25% of the EU27 average in Nord-Est in Romania to 336% in Inner London" (PDF). Eurostat.
- ↑ Èdè Creole ti Gwiyánì: Lagwiyann