Grand Bassam
Grand-Bassam (ìpè Faransé: [ɡʁɑ̃ basam]) jẹ́ ìlú kan tí ó wà ní apá Ìlà-Oòrùn orílẹ̀-èdè Ivory Coast, tí Ko fi bẹ́ẹ̀ jìnà sí ìlú Abidjan. Ìlú yí jẹ́ ikan lára àwọn tí Grand-Bassam ti ń ṣe ìjọba, ó sì tún jẹ́ ibùgbé fún àwọn ara Ivory Coast. Lásìkò ọ̀rùndún kẹrìnlélógún, Grand Bassam ni ó jẹ́ ola ìlú ati ibi tí ilé iṣẹ́ ìjọba àwọn Faransé wà làsikò ìjọba amúnisìn ní Ivory Coast. Látàrí àwọn ọ̀ṣọ̀ pàtàkì tí àwọn ìjọba amúnisìn ti ṣe lọ́jọ̀ síbẹ̀ yí, pàá pàá jùlọ bí wọ́n ṣe ṣètò ilé kíkọ́, ati bí wọ́n ṣe da ìṣèjọba amúnisìn mọ́ ìjọba ìbílẹ̀ tí wọ́n de ba níbẹ̀ pẹ̀lú àwọn ènìyàn abúléNzema. Ìtàn àgbọ́ minu ìlú náà ni ó mú ajọ UNESCO Se ìlú náà di World Heritage Site ní ọdún 2012.[3] Ní ọdún 2014, iye ònkà àwọn olùgbé ibẹ̀ Ko ju 84,028 lọ. [4]
Grand-Bassam | |
---|---|
Town, sub-prefecture, and commune | |
Colonial house in Grand-Bassam | |
Lua error in Module:Location_map at line 464: Unable to find the specified location map definition. Neither "Module:Location map/data/Ivory Coast" nor "Template:Location map Ivory Coast" exists. | |
Coordinates: 5°12′N 3°44′W / 5.200°N 3.733°WCoordinates: 5°12′N 3°44′W / 5.200°N 3.733°W[1] | |
Country | Ivory Coast |
District | Comoé |
Region | Sud-Comoé |
Department | Grand-Bassam |
Population (2014)[2] | |
• Total | 84,028 |
Time zone | UTC+0 (GMT) |
Àdàkọ:Infobox UNESCO World Heritage Site Àdàkọ:Designation list |
Bí ìlú náà ṣe rí
àtúnṣeỌ̀gbun Ébrié Lagoon nibó pín ìlú náà sí méjì ọgbọọgba, ikan ni Bassam láéláé tí ó jẹ́ ilé ìjọba fún àwọn Potogí amúnisìn tí ó dojú kọ Guinea. Ibẹ̀ ni àwọn ilé àtijọ́ tí àwọn ìjọba amúnisìn Potogí ti kọ́ tí wọ́n sì ń tún pupọ̀ nínú rẹ̀ ṣe láyé òní. Ìpín yí ni wọ́n tún ń pè ní cathedralati ilé ìṣẹ̀mbáyé fún ọ̀ṣọ́ ati ọ̀nà orílẹ̀-èdè Ivory Coast. Ó wà ní ilé ìgbé Gómìnà tẹ́lẹ̀. [3] Ipinle kejì ni Nouveau Bassam, tí ó ja pọ̀ mọ́ Bassam àtijọ́ pẹ́lú afárá tí ó wà níbẹ̀ tí ó gba orí ọ̀gbun omi kọjá. Ibi yí lo bẹ̀rẹ̀ sí ń dàgbà-sókè láti African servants' quarters tí ó sì ti di ojú ọjà báyí. Inú ìlú yí ni àwọn Roman Catholic Diocese of Grand-Bassam fi ṣe ibùjókòó, tí wọ́n sì dá Cathédrale Sacré Cœur sílẹ̀ níbẹ̀.
Ìtàn
àtúnṣeOrúkọ tí ìlú yí ń jẹ́ Bassam ni ó ṣe é ṣe kí wọ́n fàá yọ láti ara ọ̀rọ̀ ilẹ̀ adúláwọ̀ kan tí wọ́n pè ní Comoé River.[5] tí ó jẹ́ ti àwọn ènìyàn Nzema láti ọdún ọ̀rùndúpẹ̀lú kẹẹ̀dógún, abúlé náà si ojúkò okòwò àti ibi tí wọ́n ti ń pẹja. [5] Ní ọdún 1843, lẹ́yìn tí wọ́ kọwọ́ bọ̀wé àdéhùn pẹ̀lú àwọn adarí ilẹ̀ adúláwọ̀ nipa agbègbè Grand Bassam. Àwọn Fa ran se kọ́ Fort Memours sí Baba odò. [5] Ohun tí wọ́n kọ́ yí ni ó di oju ọjà àwọn Faransé ní agbègbè náà. Lẹ́yìn tí wọ́n tún ṣe àpérò Berlin ọdún 1885, agbègbè Grand Bassam tún di ibi tí àwọn amúnisìn ní ilẹ̀ adúláwọ̀ tún Se di arẹ́sẹ̀ pa. Ní ọdún 1893, wọ́n Se Grand Bassam di olú-ìlú fúnColonie de Côte d’Ivoire. Ní ọdún 1899, wọ́n gbé ilé-iṣẹ́ ìjọba kùrò ní Bassam lọ sí Bingerville látàrí àrùn ibà pọ́jú-pọ́ntọ̀ tí ó bẹ́nsílẹ̀ níbẹ̀ tí ó sì gba ẹ̀mí ìdá mẹ́ta sí mẹ́rin àwọn ènìyàn tí wọ́n ń gbé ibẹ̀.[3][5] Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé ìlú náà ni ó jẹ́ oju ko okòwò pàá pàá jùlọ òwò orí omi, ṣáájú Ki Abidjan tó gbèrú ní nkan bí ọdún 1930. Ìlú náà ti fẹ́ di ahoro tan nítorí bí Àwọn ènìyàn ṣe ti pa ibẹ̀ tí fún ọdún gbọgbọrọ. Ní ọdún 1896 tí eọ́n Ko ilé-iṣẹ́ ìjọba lọ sí Bingerville, díẹ̀ diẹ̀ ni okòwò ojú omi ń dín kù kí ó tó dópin ní ọdún 1930s. Wọ́n kó gbogbo ilé-iṣẹ́ ìjọba pátá lọ sí Abidjan lẹ́yìn tí wọ́n gba òmìnira ní ọdún 1960, tí ó sì jẹ́ wípé àwọn àjòjì gòdògbò ni eọ́n ń gbé inú Grand Bassam. Amọ́ nígbà tí yóò fi di ọdún 1970, àwọn òkunẹ̀wò ìgbafẹ́ bẹ̀rẹ̀ sí ń wá ń ṣe ibẹ̀wò sí ìlú náà. Ní inú oṣù kẹta ọdún 2016, àwọn agbésùnmọ̀mí alákatakítí ẹ̀sìn gbébọn we ìlú náà tí wọ́n sì ṣekú pa àwọn ènìyàn mọkàndínlógún which killed 19 people.[6][7]
Àwọn abúlé ibẹ̀
àtúnṣeÀwọn abúlé mẹ́jọ tí wọ́n wà ní Grand Bassam ati iye àwọn olùgbé ibẹ̀ ni àárín ọdún 2014 ni:[4]
- Azuretti (1 168)
- Ebrah (805)
- Gbamblé (341)
- Grand-Bassam (74 671)
- Modeste (1 981)
- Mondoukou (1 400)
- Vitré 1 (2 482)
- Vitré 2 (1 180)
Àwọn ìtọ́ka sí
àtúnṣe- ↑ "Ivory Coast Cities Longitude & Latitude". Sphereinfo.com. Archived from the original on 13 September 2012. Retrieved 19 November 2010. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Côte d'Ivoire". Geohive.com. Retrieved 8 December 2015.
- ↑ 3.0 3.1 3.2 "Historic Town of Grand-Bassam". UNESCO World Heritage Centre (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). United Nations Educational, Scientific, and Cultural Organization. Retrieved 2017-08-27.
- ↑ 4.0 4.1 "RGPH 2014, Répertoire des localités, Région Sud-Comoé" (PDF). ins.ci. Retrieved 5 August 2019.
- ↑ 5.0 5.1 5.2 5.3 Grand-Bassam (Côte d’Ivoire): No. 1322rev. International Council on Monuments and Sites. 14 March 2012. http://whc.unesco.org/en/list/1322/documents/. Retrieved 16 May 2021.
- ↑ Tran, Mark; Duval Smith, Alex (13 March 2016). "'At Least 16 Dead' After Gunmen Open Fire in Ivory Coast Resort". The Guardian. https://www.theguardian.com/world/2016/mar/13/gunmen-open-fire-in-ivory-coast-tourist-resort.
- ↑ Reuters