Gregory Ojefua
Gregory Ojefua (tí a bí ní ọjọ́ kẹta oṣù keje) tí a tún mọ̀ sí Greg tàbí Teddy Bear jẹ́ ọ̀ṣèré láti ìlú Naijiria, àti ólùsọ̀rọ̀ lórí ẹ̀rọ amóhùnmáwòràn
Gregory Ojefua | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Igueben, Edo State, Nigeria |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Adekunle Ajasin University |
Iṣẹ́ | actor, model, and television presenter |
Ìgbà iṣẹ́ | 2014–present |
Notable work | Gold Statue, It's Her Day, Dwindle (film), Òlòtūré |
Ìbẹ̀rẹ̀ Ìgbésí ayé àti ètò ẹ̀kọ́
àtúnṣeGregory Ojefua jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Igueben, ní ipinle Edo ní orile- orílé-ede Naijiria . Ó parí ẹ̀kọ́ alákọbẹ̀rẹ̀ rẹ̀ ní ìlú rẹ̀ kó tó lọ sí Ilé-ẹ̀kọ́ gíga Adekunle Ajasin ni Ìpínlẹ̀ Ondo tí ó ti kọ́ ẹ̀kọ́ ìṣòwò àti Ìṣàkóso ìṣòwò .
Iṣẹ́-ṣíṣe
àtúnṣeGregory Ojefua bẹ̀rẹ̀ ìṣeré láti kékeré kí ó tó mú ní ìṣẹ́ ní ọdún 2015 látàrí jíjáde rẹ̀ nínu àwọn fíìmù àgbéléwò oríṣiríṣi.
Ojefua tí kó oríṣiríṣi ipa nínu àwọn fíìmù oríṣiríṣi.
Òkìkí rẹ̀ tàn látàrí ipa Odumegwu Ojukwu tó kó nínu fíìmù "The Encounter"
Àwọn àmì ẹ̀yẹ
àtúnṣeGregory Ojefua jẹ́ àbá fún Àmì ẹ̀yẹ Òṣeré tí ó dára jù lọ nínu Ere-idaraya ni Africa Magic Viewers' Choice Awards (AMVCA) ní ọdún 2017, Ó gbà àmì ẹ̀yẹ ọ̀ṣèré tí ó dára jù lọ ní Africa International Film Festival (AFRIFF) ní ọdún 2023.