Hadiza Rabiu Shagari
Hadiza Dawaiya Shagari, tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ mọ̀ sí Hadiza Shehu Shagari (ọdun 1940/41 – ọjọ́ Kejìlá oṣù kẹjọ ọdun 2021) jẹ́ gbajúmọ̀ ènìyàn, Obìnrin àkọ́kọ́ ilẹ̀ Nàìjíríà láàrin 1979 to 1983, àti ìyàwó Shehu Shagari nígbà tí àwọn méjèèjì wà láyé.[1] Òun àti àwọn ìyàwó Shagari tó kù jẹ́ Obìnrin Àkọ́kọ́ ilẹ̀ Nàìjíríà nígbà tí Shagari jẹ́ Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà láàrin ọjọ́ kínní oṣù Kẹ̀wá ọdun 1979 sí ọjọ́ kanlélógbòn oṣù Kejìlá ọdun 1983.[2][3]
Hadiza Shagari | |
---|---|
First Lady of Nigeria | |
In role 1 October 1979 – 31 December 1983 | |
Ààrẹ | Shehu Shagari |
Asíwájú | Esther Oluremi Obasanjo |
Arọ́pò | Safinatu Buhari |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Hadiza Dawaiya Àdàkọ:Birth based on age as of date |
Aláìsí | 12 August 2021 (aged 80) Abuja, Nigeria |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Shehu Shagari (m. 1957; died 2018) |
Ìtàn ayé rẹ̀
àtúnṣeHadiza Dawaiya pàdé ọkọ rẹ̀, Shehu Shagari, ní Ìpínlẹ̀ Sókótó.[4] Wọ́n fẹ́ ara wọn ní ọdun 1957.[4]
Hadiza Shagari kú nítorí ààrùn COVID-19 ní Gwagwalada, Abuja ní ago mẹ́ta àárò ní ọjọ́ Kejìlá oṣù kẹjọ ọdun 2021.[4][5] Ó jẹ́ ọmọ ọdún ọgọrin.[6] Ìsìn kún rẹ̀ wáyé ní Abuja National Mosque ní ọjọ́ Kejìlá oṣù kẹjọ ni ago merin ọ̀sán.[4][5] Ọkọ rẹ̀, ààrẹ tẹ́lẹ̀rí Shehu Shagari, fi ayé sílè ní ọdun 2018.[6]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Shagari, Shehu Usman Aliyu (2001). Shehu Shagari : beckoned to serve : an autobiography. Ibadan: Heinemann Educational Books (Nigeria). ISBN 978-129-932-0. OCLC 50042754. https://www.worldcat.org/oclc/50042754.
- ↑ "Former Nigerian First Lady dies of COVID-19 in Abuja". Politics Nigeria. 2021-08-12. https://politicsnigeria.com/hadiza-shagari-is-dead/.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedbbc
- ↑ 4.0 4.1 4.2 4.3 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedpn2
- ↑ 5.0 5.1 "Shagari's widow, Hadiza, dies of COVID-19 complications". Vanguard (Nigeria). 2021-08-12. https://www.vanguardngr.com/2021/08/shagaris-widow-hadiza-dies-of-covid-19-complications/.
- ↑ 6.0 6.1 "Shagari wife dies: Former First Lady of Nigeria Hadiza Shehu Shagari die of Covid". BBC News. 2021-08-12. https://politicsnigeria.com/hadiza-shagari-is-dead/.