Halima Tayo Alao (tí a bi ní ọjọ́ kẹfà oṣù Kejìlá ọdún 1956) jé ayaworan ilé àti minisita teleri fún eto adugbo àti ilé nígbà sáà isejoba ààre Umaru Yar'Adua. O dipò náà mú larin ọjọ́ kẹrindínlógún oṣù keje ọdun ọdún 2007 sí ọjọ́ kàndínlọ́gbọ̀n oṣù Kẹ̀wá ọdún 2008.[1]

Halima Tayo Alao
Mínísítà fún ètò ilé àti àdúgbò
In office
26 July 2007 – 29 October 2008
AsíwájúHelen Esuene
Arọ́pòJohn Odey
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí6 December 1956
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
EducationB.Sc. (Hons) and M.Sc. (Architecture), M.Sc. Public Administration
Alma mater *Ahmadu Bello University University of Ilorin }}
ProfessionArchitect

Àárò ayé àti èkó rè àtúnṣe

A bí Halima Tayo Alao ní December 6, 1956. O ka ìwé primari àti Sekondiri rè ní ìpínlè Kano, o tèsíwájú láti gba àmì-èye B.Sc àti M.Sc rè ni Yunifásitì ti Ahmadu Bello, ipinle Kaduna ni odun 1981,[2] o tún gba àmì-èye master degree ní public administration ní yunifásitì ìlú Ìlorin(2003). O lo Advanced Management and Leadership Programme ní ilé-ìwé oko òwò ti Yunifasiti Oxford, Halima tún jé omo egbe Nigerian Institute of Architects

Isé rè àtúnṣe

Alao darapo mó osise ìjoba Kwárà State ní odun 1982. O di akowe fún èka ìjoba Ìpinlè Kwara tí o wà fún Ilé àti ilè, [3] ki o to dipe o di akowe fun eka ise àti irin ajo. O ti je alaga ìjoba agbegbe ìbílè àti akowe ìpínlè Kwara lórí òrò oun to ún se tobinrin. Laarin odun 2005 sí 2006, o je Federal minister of State fún ètò eko kotodipe o di Federal Minister of State fun ètò ilera ara.[4]

Isé rè gegebi minisita fún ètó ilé àti adugbo àtúnṣe

Ààré Umaru Yar'Adua yàn Alao sípò Minisita fun ètò Ilé àti adugbo ní 26 July 2007.[5] sùgbón ayó kuro nípò náà ní October 29, 2008.[6] Ìdí ti wón sope wón fí yó nípò náà nipé óun ma ún nija gbogbo igba pèlú Chuka Odom, minisita fun state ati asoju egbé oselu Progressive Peoples Alliance.[7] John Odey ní eni tí a yàn láti ropo rè ni 17 December, 2008.

Àwon Ìtókasí àtúnṣe

  1. "About Halima Tayo Alao: Civil servant (1956-) - Biography, Facts, Career, Life". peoplepill.com. 1956-12-06. Retrieved 2022-05-29. 
  2. "Halima Tayo Alao's biography, net worth, fact, career, awards and life story". ZGR.net. 2020-07-15. Retrieved 2022-05-29. 
  3. Gbadeyanka, Modupe (2019-10-23). "Former Minister Leaves Board of UACN Property". Business Post Nigeria. Retrieved 2022-05-29. 
  4. "Nigeria Ministers". Worldwide Guide to Women in Leadership (in Èdè Ilẹ̀ Denmark). 2009-04-21. Archived from the original on 2009-04-21. Retrieved 2022-05-29.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. "AfricaNews - Articles". Nigeria: Yar'Adua names cabinet (in Èdè Dọ́ọ̀ṣì). 2011-09-28. Archived from the original on 2011-09-28. Retrieved 2022-05-29.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. "The Sun News On-line". sunnewsonline.com. 2010-08-17. Archived from the original on 2010-08-17. Retrieved 2022-05-29.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  7. "NewsWatchngr- The Best Reviews and Buyer's Guide". NewsWatchngr - The Best Reviews and Buyer's Guide. 2018-04-05. Retrieved 2022-05-29.