Umaru Musa Yar'adua
Umaru Musa Yar'Adua (16 August, 1951 - 5 May, 2010[1]) je Aare Naijiria keji ni Igba Oselu Ekerin ni orile-ede Naijiria. O je Gomina Ipinle Katsina lati 29 May, 1999 titi di 28 May, 2007.
Umaru Musa Yar'Adua | |
---|---|
![]() | |
Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà | |
In office 29 Oṣù Kàrún 2007 – 5 Oṣù Kàrún 2010 | |
Vice President | Goodluck Jonathan |
Asíwájú | Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́ |
Arọ́pò | Goodluck Jonathan |
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Katsina | |
In office 29 Oṣù Kàrún 1999 – 29 Oṣù Kàrún 2007 | |
Asíwájú | Joseph Akaagerger |
Arọ́pò | Ibrahim Shema |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Kàtsínà, Nàìjíríà | 16 Oṣù Kẹjọ 1951
Aláìsí | 5 May 2010 Aso Rock, Abuja, Nigeria | (ọmọ ọdún 58)
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Ẹgbẹ́ Olóṣèlúaráìlú àwọn Aráàlù (1998–dòní) |
Other political affiliations | People's Redemption Party (Before 1989) Social Democratic Party (1989–1998) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Turai Yar'Adua (1975–2010) Hauwa Umar Radda (1992–1997) |
Alma mater | Barewa College Yunifásítì Àmọ́dù Béllò |
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn ìtọ́kasíÀtúnṣe
Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Umaru Musa Yar'adua |