Kesari (fíìmù 2018)
Kesari jẹ́ fíìmù Yorùbá ti Nàìjíríà tó jáde ní ọdún 2018[1], èyí tí Ibrahim Yekini gbé jáde. Tope Adebayo sì ni olùdarí fíìmù yìí.[2][3][4]
Ìṣàgbéjáde
àtúnṣeNínú ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nùwo kan, Ibrahim Yekini tó jẹ́ òǹkọlwé àti olùgbéjáde sọ ọ́ di mímọ̀ pé fíìmù Black Panther tí òun wò ló fún òun ní ìwúrí láti kọ fíìmù yìí.[5]
Àwọn akópa
àtúnṣe- Femi Adebayo
- Ibrahim Yekini
- Akin Olaiya
- Kemi Afolabi
- Adebayo Salami
- Muyiwa Ademola
- Toyin Abraham
- Antar Laniyan
- Bimbo Akintola Odunlade
Ìsọníṣókí
àtúnṣeỌlọ́ṣà kan tó ní oògùn burúkú lọ́wọ́ pàdé ẹni tó kápá rẹ̀, àmọ́ ọlọ́pàá ni ẹni yìí jẹ́.
Àwọn àmì-ẹ̀yẹ
àtúnṣeFíìmù yìí gba àmì-ẹ̀yẹ fún fíimù tó dára jù àti olùgbéjáde tó dára jù ní abẹ́ ìsọ̀rí fíìmù Yorùbá ní ayẹyẹ City People Entertainment Awards.[6]
Àwọn èyí tó tẹ̀le
àtúnṣeFìímù náà ni apá mẹ́ta, tí í ṣe: Kesari 2, Return of Kesari, àti Return of Kesari 2. Yekini gba àmì-ẹ̀ye fún òṣèré tó dára jù lọ ní ayẹyẹ Best of Nollywood Awards, ti ọdún 2019, fún ìkópa rẹ̀ nínú fíìmù Return of Kesari.[7]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Àdàkọ:Cite AV media
- ↑ Online, Tribune (2019-07-06). "Why I dumped boxing for acting —Actor Itele". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-30.
- ↑ "I was inspired by Black Panther to write Kesari – Itele". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-07-21. Retrieved 2022-07-30.
- ↑ Alao, Biodun (2019-10-14). "ITELE's New Movie, KESARI Gathers 1.8 Million Views". City People Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-30.
- ↑ "I was inspired by Black Panther to write Kesari – Itele". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-07-21. Retrieved 2022-07-30.
- ↑ Reporter (2019-10-14). "Yoruba Movie Winners Emerge @ City People Movie Awards". City People Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-30.
- ↑ "Best Of Nollywood Lights Up Kano". The Guardian Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-12-21. Archived from the original on 2019-12-21. Retrieved 2022-07-30.