Látfíà (Àdàkọ:Lang-lv), lonibise bi Orile-ede Olominira ile Látfíà (Àdàkọ:Lang-lv) je orile-ede ni agbegbe Baltiki ni Apaariwa Europe. O ni bode ni ariwa mo Estonia (343 km), ni guusu mo Lithuania (588 km), ni ilaorun mo Rosia (276 km), ati ni guusuilaorun mo Belarus (141 km).[4] Niwaju Omi-okun Baltiki ni iwoorun ni Swidin wa. Agbegbe Látfíà borile to to 64,589 km2 (24,938 sq mi) o si ni ojuoju tutu kakiri odun.

Republic of Latvia
Latvijas Republika
Àsìá Àmì ọ̀pá àṣẹ
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdè"God bless Latvia!"  
(Àdàkọ:Lang-lv)
Ibùdó ilẹ̀  Látfíà  (dark green) – on the European continent  (light green & dark grey) – in the European Union  (light green)  —  [Legend]
Ibùdó ilẹ̀  Látfíà  (dark green)

– on the European continent  (light green & dark grey)
– in the European Union  (light green)  —  [Legend]

Olúìlú
(àti ìlú títóbijùlọ)
Riga
56°57′N 24°6′E / 56.95°N 24.1°E / 56.95; 24.1
Èdè àlòṣiṣẹ́ Latvian
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn  62.1% Latvians
26.9% Russians
  3.3% Belarusians
  2.2% Ukrainians
  5.5% others[1]
Orúkọ aráàlú Ará Latvia
Ìjọba Parliamentary republic
 -  President Raimonds Vējonis
 -  Prime Minister Māris Kučinskis
Independence from German Empire and Russia 
 -  Declared1 November 18, 1918 
 -  Recognized January 26, 1921 
 -  Soviet occupation August 5, 1940 
 -  Nazi German occupation July 10, 1941 
 -  Soviet occupation 1944 
 -  Announced May 4, 1990 
 -  Restored September 6, 1991 
Ọmọ ẹgbẹ́ EU May 1, 2004
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 64,589 km2 (124th)
24,938 sq mi 
 -  Omi (%) 1.57% (1,014 km2)
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2016 1,953,200 (148rd)
 -  2011 ppl census 2,067,887 [2] 
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 34.3/km2 (166th)
89.0/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2009
 -  Iye lápapọ̀ $32.234 billion[3] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $14,254[3] 
GIO (onípípè) Ìdíye 2009
 -  Àpapọ̀ iye $26.247 billion[3] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $11,607[3] 
Gini (2003) 37.7 (medium
HDI (2008) 0.866 (high) (48th)
Owóníná Euro (EUR)
Àkókò ilẹ̀àmùrè EET (UTC+2)
 -  Summer (DST) EEST (UTC+3)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ right
Àmìọ̀rọ̀ Internet .lv
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù +371
1 Latvia is de jure continuous with its declaration November 18, 1918.ItokasiÀtúnṣe

  1. Population Census 2011 - Key Indicators
  2. Census 2011: Latvia, (Gẹ̀ẹ́sì)
  3. 3.0 3.1 3.2 3.3 "Latvia". International Monetary Fund. Retrieved 2010-04-21. 
  4. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named CIAFactbook