Lindsay Ann Davenport (ojoibi June 8, 1976 ni Palos Verdes, California) je agba tenia ara Amerika to je eni Ipo No. 1 Lagbaye tele. O gba ife-eye idije Grand Slam enikan meta ati wura ni Olimpiki ni idije enikan.

Lindsay Davenport
Davenport Lindsay.jpg
Orílẹ̀-èdè United States
Ibùgbé Laguna Beach, California
Ọjọ́ìbí Oṣù Kẹfà 8, 1976 (1976-06-08) (ọmọ ọdún 43)
Palos Verdes, California
Ìga 1.89 m (6 ft 2+12 in)
Ìgbà tódi oníwọ̀fà 1993
Ìgbà tó fẹ̀yìntì 2011
Ọwọ́ ìgbáyò Right-handed (two-handed backhand)
Ẹ̀bùn owó US$22,144,735[1]
(4th in all-time rankings)
Iye ìdíje 753–194 (79.5%)
Iye ife-ẹ̀yẹ 55
Ipò rẹ̀ gígajùlọ No. 1 (October 12, 1998)
Open Austrálíà W (2000)
Open Fránsì SF (1998)
Wimbledon W (1999)
Open Amẹ́ríkà W (1998)
Ìdíje WTA W (1999)
Ìdíje Òlímpíkì Gold medal.svg Gold medal (1996)
Iye ìdíje 382–115
Iye ife-ẹ̀yẹ 38 (1 ITF)
Ipò rẹ̀ gígajùlọ No. 1 (October 20, 1997)
Open Austrálíà F (1996, 1997, 1998, 1999, 2001, 2005)
Open Fránsì W (1996)
Wimbledon W (1999)
Open Amẹ́ríkà W (1997)
Last updated on: April 14, 2008.
Iye ẹ̀ṣọ́ Olympiki
Women's tennis
Adíje fún the  United States
Wúrà 1996 Atlanta Women's singles


ItokasiÀtúnṣe