Lucie Šafářová (bíi ní Ọjọ́ kẹrin Oṣù kejì Ọdún 1987) jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n agbá tenis ọmọ orílẹ̀ èdè Czech lati Brno.[1]

Lucie Šafářová
Lucie Šafářová at the 2015 Indian Wells Masters
Orílẹ̀-èdè Czech Republic
IbùgbéBrno, Czech Republic
Ọjọ́ìbí4 Oṣù Kejì 1987 (1987-02-04) (ọmọ ọdún 37)
Brno, Czechoslovakia
(now Czech Republic)
Ìga1.77 m (5 ft 10 in)
Ìgbà tódi oníwọ̀fà2002
Ọwọ́ ìgbáyòLeft-handed (two-handed backhand)
Ẹ̀bùn owó$6,229,542
Ẹnìkan
Iye ìdíje364–254 (58.9%)
Iye ife-ẹ̀yẹ6 WTA, 7 ITF
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 7 (8 June 2015)
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́No. 7 (8 June 2015)
Grand Slam Singles results
Open AustrálíàQF (2007)
Open FránsìF (2015)
WimbledonSF (2014)
Open Amẹ́ríkà4R (2014)
Ẹniméjì
Iye ìdíje97–113 (46.19%)
Iye ife-ẹ̀yẹ6 WTA, 1 ITF
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 15 (3 February 2014)
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́No. 22 (23 March 2015)
Grand Slam Doubles results
Open AustrálíàW (2015)
Open FránsìF (2015)
WimbledonQF (2014)
Open Amẹ́ríkà3R (2013)
Àwọn Ìdíje Ẹgbẹ́ Agbáyò
Fed CupW (2011, 2012, 2014)
Record 13–13
Last updated on: 4 May 2015.


Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Qualifier Safarova lands Estoril title". Eurosport. 1 May 2005.