Lukman Shobowale
Lukman Olawale Shobowale (tí á bí ní Ọjọ́ kàndínlọ́gbọ̀n oṣù karùn-ún ọdún 1994) jẹ́ Onkọ́wé atí Onísòwò Nàìjíríà. Òún ní olùdásílẹ̀ atí Alàkóso Dukiya Investments.[1]
Lukman Shobowale | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Lukman Olawale Shobowale 29 Oṣù Kàrún 1994 |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Ilorin, Ajayi Crowther University, Lagos Business School |
Iṣẹ́ | Olùgbéejáde ọhún-iní gídí atí Onkọ́wé |
Gbajúmọ̀ fún | CEO/Co-founder Dukiya Investments |
Olólùfẹ́ | Oluwapelumi Shobowale |
Website | lukmanshobowale.com/ |
Ìgbésíayé
àtúnṣeLukman ní olùdásílẹ̀ tí Dukiya Investments Limited, ilé-iṣẹ́ ìdàgbàsókè ọhun-iní gídí kán tí ọ dà lórí Èkó.[2][3][4] Ọ jẹ́ onkọ́wé atí tún ṣé iranṣẹ́ bí olórí Ìdàgbàsókè Ìṣòwò ní Dukiya Investments LTD. Lukman jẹ́ olókìkí fún ọhun-iní gídí, ìṣòwò, kíkọ, atí adári.[5][6] Ọ ṣé agbéró fún lílò ọhun-iní gídí láti kọ́ ọ́rọ̀ fún àwọn ìran iwájú. Làkọkó iwé-ẹ̀kọ́ oyè rẹ ní History and International Studies ní Ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásítì ìlú Ilorin, ọ ṣíṣẹ́ bí Alàkóso Ẹgbẹ́ ọmọ ilé-ìwé fun6 ọdún ẹ̀kọ́ 2016/2017.[7] Lukman gba Aami-ẹ́ri Ìṣòwò 2023 ní ọdún 2023 nípaṣẹ The Future Awards Africa.[8]Lukman jẹ́ oluyọ́ọ́da tí ọ tún ṣé àwọn iṣẹ́ aláànu.[9][10]
Ẹ̀kọ́
àtúnṣeLukman jẹ́ ọmọ ilé-ẹ̀kọ́ tí Yunifásítì ìlú Ilorin, níbití ọ tí kọ́ ẹ̀kọ́ Ìtàn atí Ìjìnlẹ̀ Káríayé fún Bachelor of Art Degree ṣáájú kí ọ tọ lọ́ sí Ilé-ẹ̀kọ́ Ajayi Crowther University fún Masters ní Ìṣàkóso Ìṣòwò ní ọdún 2021.[11] Ọ tún lọ́ síwájú sí Ilé-ìwé Ìṣòwò tí Èkó fún Ẹtọ Àwọn Alàkóso Ọlọhun.[11][12] Ọ ní àwọn ẹtọ aláṣẹ ní Ilé-ìwé Ìṣòwò Rome ní ọdún 2023 atí Ilé-ìwé Ìṣòwò Ìlú Lọndọnu ní ọdún 2024.[13]
Àwọn ìwé ọhún
àtúnṣeÌgbésí ayé ará rẹ
àtúnṣeỌ ní ìyàwó sí Oluwapelumi Shobowale pẹlú ọmọbìnrin kán.
Àwọn ẹbùn
àtúnṣe- 2023 Entrepreneur of the Year Prize by The Future African Awards[16]
- The Entrepreneur of the year at the Real Estate Conference and Recognition Award (RECRA 2023)[17]
- The Top 100 Nigerian Youth Leaders by the Ọọ̀ni Ifẹ̀, Ọbá Adéyẹyè Ẹnitàn Ògúnwúsì, honored Lukman as one of the young Nigerians leading the way in the leadership and business arenas in 2020.[18][19]
- 2016 Peace Ambassador in Kwara State.[20]
Àwọn ìtọkásí
àtúnṣe- ↑ Rapheal (2023-05-31). "Lukman Shobowale, Paul Olajide among realtors going strong". The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-06-21.
- ↑ "Dukiya investments rebrand cooperate identity to deliver excellent service". BusinessDayNG (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Jan 31, 2022. Retrieved June 21, 2023.
- ↑ housingcablemgr (2023-01-06). "YOUNG REAL ESTATE PLAYERS TO WATCH IN 2023 - Housing Cable Nigeria" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-06-21.
- ↑ "Lukman Shobowale's Dukiya Investment rated among top 100 SMEs in Nigeria". The Lekki Post (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2023-01-29. Retrieved 2023-06-21.
- ↑ "Antidote to Housing Deficit in Nigeria - THISDAYLIVE". www.thisdaylive.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-06-21.
- ↑ "Addressing the housing deficit in Nigeria". TheCable (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2023-02-15. Retrieved 2023-06-21.
- ↑ "University of Ilorin Student Union History". UnilorinSU.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved June 21, 2023.
- ↑ Africa, Glamour South (October 21, 2023). "Meet the Future Awards Africa 2023 Nominees". Glamour SA (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved March 22, 2024.
- ↑ Suleiman, Yemisi (January 7, 2024). "Bayo Lawal And Lukman Shobowale: Defining New Trends in Real Estate". Vanguard Allure (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved March 22, 2024.
- ↑ Unilorin, Ucj (May 9, 2023). "Lagos Real Estate Chiefs Storm Unilorin for AESA Leadership and Entrepreneurship Summit – UCJ UNILORIN". UCJ UNILORIN (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved March 23, 2024.
- ↑ 11.0 11.1 Nigeria, Guardian (December 11, 2022). "Dukiya co-founders complete executive programme at Lagos Business School". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved June 22, 2023.
- ↑ housingcablemgr (2023-01-06). "YOUNG REAL ESTATE PLAYERS TO WATCH IN 2023 - Housing Cable Nigeria" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-06-21.
- ↑ "Real Estate Entrepreneur Lukman Shobowale Completes Executive Programme at London Business School". THISDAYLIVE (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). March 23, 2024. Retrieved March 23, 2024.
- ↑ Ibeh, Ifeanyi (2023-07-07). "Lukman Shobowale announces book on Nigeria's real estate and housing potential". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2023-08-04. Retrieved 2023-08-04.
- ↑ Reporter (2017-09-27). "The book titled - Emerge! like a lotus in the pond by Lukman Shobowale.". City People Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-08-04.
- ↑ "Real estate solidified my interest in entrepreneurship, people – Lukman Shobowale". Tribune Online NG (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). November 1, 2023. Retrieved November 2, 2023.
- ↑ "Lukman Shobowale bags RECRA's 2023 'Entrepreneur Of The Year'". Leadership.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2023-05-21. Retrieved June 21, 2023.
- ↑ Rasak, Adekunle (2020-01-17). "Shobowale clinches Ooni's '100 Nigerian youth leaders' award". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-06-21.
- ↑ housingcablemgr (2023-01-06). "YOUNG REAL ESTATE PLAYERS TO WATCH IN 2023 - Housing Cable Nigeria" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-06-21.
- ↑ "Unilorin Bulletin 7th November, 2016". Issuu (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). November 7, 2016. Retrieved June 22, 2023.