Marin Čilić
Marin Čilić[1] (Àdàkọ:IPA-hr; ojoibi 28 September 1988) je agba tenis ara Kroatia. O gba ife-eye idije Open Amerika 2014 awon okunrin enikan.[2]
Čilić at the 2014 Madrid Open | |
Orílẹ̀-èdè | Kroatíà |
---|---|
Ibùgbé | Monte Carlo, Monaco |
Ọjọ́ìbí | 28 Oṣù Kẹ̀sán 1988 Međugorje, SR Bosnia and Herzegovina, SFR Yugoslavia |
Ìga | 1.98 m (6 ft 6 in) |
Ìgbà tódi oníwọ̀fà | 2004 |
Ọwọ́ ìgbáyò | Right-handed (two-handed backhand) |
Olùkọ́ni | Bob Brett (2004–2013) Goran Ivanišević (2013–) |
Ẹ̀bùn owó | $10,722,989 |
Ẹnìkan | |
Iye ìdíje | 291–160 (64.38%) |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 12 |
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 9 (22 February 2010) |
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ | No. 9 (8 September 2014) |
Grand Slam Singles results | |
Open Austrálíà | SF (2010) |
Open Fránsì | 4R (2009, 2010) |
Wimbledon | QF (2014) |
Open Amẹ́ríkà | W (2014) |
Àwọn ìdíje míràn | |
Ìdíje Òlímpíkì | 2R (2008, 2012) |
Ẹniméjì | |
Iye ìdíje | 59–65 |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 0 |
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 49 (15 April 2013) |
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ | No. 111 (8 September 2014) |
Last updated on: September 8, 2014. |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "The pronunciation by Marin Čilić himself". ATP World Tour. Retrieved 22 October 2017.
- ↑ "Cilic to Make Debut". Barclays ATP World Tour Finals. 18 October 2014. http://www.barclaysatpworldtourfinals.com/en/news-and-media/tennis/finals-2014-cilic-qualifies.