Mombasa ni ilu Ekeji ti o tobijulo ni orile ede Kenya, lehin Ilu Nairobi, ti o je OluIlu Orile Ede naa. Ilu naa wa ni eti Bebe okun India, ni iha Ila Orun si Ilu Nairobi.

Mombasa
Tusks in Mombasa
Tusks in Mombasa
Location of Mombasa
Country  Kenya
Province Coast Province
District Mombasa District
Ìjọba
 • Mayor Ahmed Abubakar Mohdhar [1]
Ìtóbi
 • City 295 km2 (114 sq mi)
 • Land 230 km2 (90 sq mi)
 • Water 65 km2 (25 sq mi)
Elevation Àsìṣe ìgbékalẹ̀ọ̀rọ̀: àmì-ìṣírò * àìretí m (Àsìṣe ìgbékalẹ̀ọ̀rọ̀: àmì-ìṣírò / àìretí ft)
Agbéìlú (1999)
 • City 707,400[citation needed]
 • Ìgboro 707,400[citation needed]
Time zone EAT (UTC+3)


ItokasiÀtúnṣe

  1. The Standard, July 3, 2009: Mombasa mayor earns new term