Ọ̀bọ

(Àtúnjúwe láti Monkey)

Ọ̀bọ[1] jẹ́ orúkọ tí a mọ̀ àwọn ẹ̀yà ẹranko tí wọ́n jẹ́ elégungun afọ́mọ-lọ́mú tí wọ́n tún ń pè ní (infraorder Simiiformes), tábí (simians) ní èdè Gẹ̀ẹ́sì. Àká àwọn ẹranko tí a ti mẹ́nu bà lókè yí (ọ̀bọ), ni a mọ̀ ọb̀ọ yàtọ̀ sí Ìnàkí tí kò sí lára wọn bí ó tílẹ̀ jẹ́ wípé ìṣesí kan náà ní wọ́n ní. Àmọ́ lọ́pọ̀ ìgbà, wọ́n má n ka ìnàkí mọ́ àwọn ọ̀bọ.[2]

Ọ̀bọ
Monkeys
Temporal range: Oligocene–Present
A young male White-fronted Capuchin (Cebus albifrons).
Ìṣètò onísáyẹ́nsì
Ìjọba:
Ará:
Ẹgbẹ́:
Ìtò:
Àwọn Àdìpọ̀ Abẹ́

Ni ọdun 1812, ọgbẹni Geoffroy ṣe akojopo awon inaki ti o si pe won ni ''Catarrhini'' ti won je awon obo aye atijo. Awon inaki tuntun aye ode oni ni Geoffroy pe ni ''Platyrrhini''.[3]

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Monkey - Definition, Characteristics, Types, Classification, & Facts". Encyclopedia Britannica. 1998-07-20. Retrieved 2023-02-11. 
  2. "Monkey". San Diego Zoo Animals & Plants. Retrieved 2023-02-11. 
  3. "Catarrhini É.Geoffroy, 1812". GBIF. Retrieved 2023-02-11.