Nosa Omoregie
It has been suggested that this article be merged with Àdàkọ:Pagelist. (Discuss) |
Nosa Omoregie | |
---|---|
Orúkọ àbísọ | Nosa Omoregie |
Ọjọ́ìbí | 26 Oṣù Kejì 1981 Edo State, Nigeria |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Benin City, Edo State, Nigeria |
Irú orin | CCM, Contemporary worship music, Gospel |
Occupation(s) | Singer-songwriter, performer, worship leader, musician, producer |
Instruments | Vocals, Piano,Guitar |
Years active | (2009–present) |
Labels | Chocolate City, Salt Music |
Associated acts | Nathaniel Bassey, MI, Ice Prince, Zee, Masterkraft, Frank Edwards, Dammy Krane, Sasha P, Seyi Shay, Milli |
Website | saltmusic.ng |
Nosa Omoregie, tí a mọ̀ mọ́ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí i Nosa, jẹ́ oníṣẹ́-ọnàNàìjíríà, olórin, a-kọ-orin àti eléré. Ó wà lábẹ́ Warner Music Group African partner lọ́wọ́lọ́wọ́, Chocolate City.[1][2]
- ↑ Animashaun, Ayo (27 October 2013). "The Difference between Church and Gospel Music – Nosa". Hip Hop World Magazine. Archived from the original on 26 August 2014. Retrieved 2014-08-22.
- ↑ Nwamu, Aniebo (30 March 2014). "'Marriage Not on My Mind Yet' – Nosa | Nigerian News from Leadership Newspapers". Leadership.ng. Retrieved 2014-08-22.
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ìgbé-ayé
àtúnṣeNosa Omoregie, tí wọ́n mọ̀ ní ṣókí gẹ́gẹ́ bí i Nosa, ni wọ́n bí ní 26 oṣù kejì ọdún 1981, ó jẹ́ ọmọ ìlú Benin City, Ìpínlẹ̀ Edo.
Ẹ̀kọ́
àtúnṣeÓ kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ ẹ̀rọ ní Yunifásítì Benin (UNIBEN). Ìpínlẹ̀ Edo [1]
- ↑ "What I want in my woman – Nosa Omoregie". Punchng.com. 6 July 2014. Archived from the original on 22 August 2014. Retrieved 2014-08-22.
Iṣẹ́
àtúnṣeOrísun ayọ̀ Nosa gẹ́gẹ́ bí ọmọ tí ó ń dàgbà wà nínú orin àti lílọ sí ilé ìjọsìn, níbi tí ó ti bẹ̀rẹ̀ sí ṣe àmúlò àwọn ẹ̀bùn rẹ̀ tí ń gbèrú. Ó bẹ̀rẹ̀ nínú ẹgbẹ́ akọrin ọmọdé ní ilé ìjọsìn, àwọn olórin ẹ̀mí bí i Fred Hammond àti Kim Burrell sì ni wọ́n jẹ́ ẹṣin iwájú tí ó ń wò sáré àti àwọn ẹgbẹ́ olórin R n B Boyz II men. Ó ní láti nífẹ̀ẹ́ orin jazz àti orin soul àti lẹ́yìn náà orin rock nígbà tí ó yá, fún rírọrùn tí ó rọrùn. Ó tún jẹ́ aṣàwòkọ́ṣe ńlá Afro-Highlife[1] pàápàá orin láti ọwọ́ Sonny Okosun, Christy Essien-Igbokwe, King Sunny Adé àti Onyeka Onwenu, fún ìdí èyí ó mú láti inú ọ̀pọ̀ èròǹgbà ọmọdé fún iṣẹ́ láti di onímọ̀ ẹ̀rọ, jagunjagun, agbábọ́ọ̀lù sí dídi aṣàgbéjáde orin àti olórin.[2]
Èròǹgbà Nosa pẹ̀lú iṣẹ́ orin rẹ̀ ni láti dí àlàfo irúfẹ́ orin nígbà tí ó ń rí i dájú pé abala orin ẹ̀mí rẹ̀ wà ní ipele iwájú pátápátá gẹ́gẹ́ bí àwọn irúfẹ́ orin mìíràn èyí ni pé irúfẹ́ àpapọ̀ tí ó jẹ́ àrà ọ̀tọ̀: tí ó ń ṣe àtinúdá orin ẹ̀mí lórí ìlù high-life , ẹsẹ high-life pẹ̀lú ègbè tí ó jọ mọ́ rock-y tàbí kíkọ orin 'àdàmọ̀dì' Òyìnbó pẹ̀lú àdídùn R n B nígbà tí ó bá ń ṣe ìwàásù iṣẹ́ amóríwú tàbí amọ́kànyá sí àwọn olùgbọ́ rẹ̀. .[1]
Wọ́n ṣe àgbéjáde àwo orin rẹ̀ àkọ́kọ́, Open Doors, ní 14 oṣù kẹta 2014 ó sì ṣe àtìlẹ́yìn rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ẹyọ orin "Always Pray for You", "Why You Love Me" àti "Always on My Mind".[3] Àti bákan náà ní oṣù karùn-ún 2014, ó pawọ́pọ̀ pẹ̀lú Nokia fún àgbéjáde orin rẹ̀ "Love is Calling".[4] Ní ọjọ́ 16 oṣù karùn-ún 2014, ìwé ìròyìn The Punch sọ pé Nosa tọwọ́bọ̀wé àdéhùn iṣẹ́ ìpolówó pẹ̀lú Unilever.[5] Ní ọjọ́ 26, oṣù kejì 2020, tí ó tún jẹ́ ọjọ́ ìbí rẹ̀, Nosa bẹ̀rẹ̀ ilé-iṣẹ́ orin rẹ̀ Salt Music.[6]
Iṣẹ́ orin àti orin-ẹyọ tí ó gbé e jáde
àtúnṣeNosa lọ sí abẹ́ ilé-iṣẹ́ orin Chocolate City ní 2012.[7] Ní 11 oṣù kọkànlá 2009 Nosa ṣe àgbéjáde orin-ẹyọ rẹ̀ àkọ́kọ́, "Always Pray for You", lábẹ́ ilé-iṣẹ́ Chocolate City. "Always Pray for You" jẹ́ ẹyọ-orin Nosa àkọ́kọ́ .[8]
- ↑ 1.0 1.1 "What I want in my woman – Nosa Omoregie". Punchng.com. 6 July 2014. Archived from the original on 22 August 2014. Retrieved 2014-08-22.
- ↑ "Becoming a soldier was my biggest dream as a child –Nosa Omoregie". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-08-23.
- ↑ "Chocolate City's NOSA Drops Debut Album". P.M. NEWS Nigeria. 14 March 2014. Retrieved 2014-08-22.
- ↑ "Nokia Endorses NOSA". P.M. NEWS Nigeria. 28 May 2014. Retrieved 2014-08-22.
- ↑ "Nosa grabs licensing deal with Close-Up". Punchng.com. 16 May 2014. Archived from the original on 5 July 2014. Retrieved 2014-08-22.
- ↑ Nicegospel (2020-02-29). "Nosa Floats Record Label – Salt Music » Nicegospel". Nice Gospel » Download Latest Gospel Songs 2019 / 2020 (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 5 October 2022. Retrieved 2020-03-13.
- ↑ "Chocolate City records signs nosa". Hip Hop World Magazine. Archived from the original on 26 August 2014. Retrieved 20 August 2014.
- ↑ "Nosa – Always Pray For You". notjustok.com. Archived from the original on 26 August 2014. Retrieved 20 August 2014.
Àtòjọ orin rẹ̀
àtúnṣeÀwo
àtúnṣe- Open Doors (2013)[1]
Orin-ẹyọ
àtúnṣeỌdún | Àkọ́lé | Àwo |
---|---|---|
2009 / 2013 | "Always Pray for You" | Open Doors |
2013 | "Why You Love Me" | |
2014 | "Always on My Mind" | |
2016 | "I am Blessed"[2] | |
2016 | "God Is Good"[3] | |
2017 | "Most High" (feat. Nathaniel bassey)[4] | |
2018 | "We Will Arise" (feat. LCGC)[5] | |
2019 | Na Your Way Ft. Mairo Ese [6] | |
2020 | "Dry Bones" | |
2014 | "Always on My Mind (Remix)"
(Nosa featuring MI) |
Non Album Singles |
2011 | "Standing"
(Zee featuring Nosa) |
Non-album single |
2013 | "New Day"
(Masterkraft featuring Frank Edwards, Nosa) | |
2014 | "Fly Like The Eagles"
(Ice Prince featuring Dammy Krane, Sasha P, Seyi Shay) |
- ↑ "Nosa walks into the door Jeremiah Gyang once opened [Album Review] | Nigerian Entertainment Today – Nigeria's Number 1 Entertainment Daily". Thenet.ng. Archived from the original on 31 August 2014. Retrieved 2014-08-22. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Gerardcole (2016-10-02). "Music: Nosa - Blessed". NetNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-06-14.
- ↑ "Nosa - 'God is good'". www.pulse.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-09-29. Retrieved 2019-06-14.
- ↑ "'Most high' ft Nathaniel Bassey". www.pulse.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-07-03. Retrieved 2019-06-14.
- ↑ "MUSIC: Nosa – We Will Arise". 360Nobs.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-09-14. Archived from the original on 24 September 2020. Retrieved 2019-06-14.
- ↑ "Listen To Nosa's Genuine Description Of God In "Na Your Way"". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-09-30. Archived from the original on 19 June 2022. Retrieved 2019-10-03.