Ọlágúnsóyè Oyinlọlá
Olóṣèlú
(Àtúnjúwe láti Olagunsoye Oyinlola)
Ọlágúnsóyè Oyinlọlá (ojoibi February 3, 1951) je omo ologun to tifeyinti ati oloselu omo ile Naijiria. Ó jẹ́ alámóójútó ológun fún Ìpínlẹ̀ Èkó láti 1993 de 1996. Ní ìgbà òṣèlú ẹ̀ẹ̀kejì, wọ́n dìbò yàn bí Gomina Ipinle Osun lati 29 May, 2003 de 26 November 2010[1] nigbati ile-ejo fagile idiboyan re sipo fun igba keji gege bi gomina ninu idiboyan 2007.
Ọlagunsoye Oyinlọla | |
---|---|
Olagunsoye Oyinlola (left) with Femi Fani-Kayode at a reception in 2007 | |
Administrator of Lagos State | |
In office December 1993 – August 1996 | |
Asíwájú | Michael Otedola |
Arọ́pò | Buba Marwa |
Governor of Osun State | |
In office May 2003 – 26 November 2010 | |
Asíwájú | Adebisi Akande |
Arọ́pò | Rauf Aregbesola |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | February 3, 1951 Okuku, Odo Ọtin LGA, Ọṣun State |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | PDP |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣeÌkìlọ̀: Bọ́tìnì ìtò àkọ́kọ́ṣe "Ọlágúnsóyè, Oyinlọlá" dípò Bọ́tìnì ìtò àkọ́kọ́ṣe "Oyinlola Olagunsoye" tẹ́lẹ̀.