Olufemi Terry

Oníwé-Ìròyín

Olufemi Terry jẹ́ òǹkọ́wé ara Sierra Leone. Ó gba ẹ̀bùn Caine Prize for African Writing ti ọdún 2010 fún ìwé kékeré ẹlẹ́ẹ̀kejì rẹ̀, tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Stickfighting Days," èyí tí wọ́n kọ́kọ́ tẹ̀ jáde ní Chimurenga.[1] Àwọn adájọ́ náà sọ pé ó jẹ́ "tálẹ̀ǹti kan pẹ̀lú ọjọ́-iwájú tó dára".[2] Ó lérò láti ṣàtẹ̀jáde ìwé kejì láìpẹ́.

Olufemi Terry
Ọjọ́ ìbíSierra Leone
Iṣẹ́Writer, journalist
SubjectAfrican diaspora
Notable works"Stickfighting Days",
The Sum of All Losses
Notable awardsCaine Prize for African Writing (2010)

Ayé rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Terry sí ìlú Siẹrra Léònè, àmọ́ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan àti Côte d'Ivoire ni ó dàgbà sí, ó sì kẹ́kọ̀ọ́ ní New York, United States,[3] kí ó tó di akọ̀ròyìn ní Somalia àti Uganda.[4] Ìlú Stuttgart, ní Germany ló ń gbé báyìí.[3] Ó gboyè MA nínú ẹ̀kọ́ creative writing ní University of Cape Town ní ọdún 2008.[5]

Ní 5 July 2010, Terry gba ẹ̀bùn Caine Prize fún African Writing, ṣị́wájú àwọn òǹkọ̀wé ilè Afirika mìíràn bí i Ken Barris (South Africa), Lily Mabura (Kenya), Namwali Serpell (Zambia), àti Alex Smith (South Africa).[6][7]

Terry sọ ọ́ di mímọ̀ pé "ìyàlẹ́nu bọ òun fún wákàtí kan àkọ́kọ́". Ó gba ẹ̀bùn £10,000 ní London.[4] Ó sì tún le lo oṣù kan ní Georgetown University, ní United States.[4]

Iṣẹ́ rẹ̀

àtúnṣe

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Flood, Alison (6 July 2010). "Olufemi Terry wins Caine prize for African writing". The Guardian (London). https://www.theguardian.com/books/2010/jul/06/olufemi-terry-wins-caine-prize. Retrieved 6 July 2010. "Mormegil is as long as our regulations allow, a lovely willow poke, dark willow – that's why I chose the name. It means black sword in Tolkien's language. – Quote from "Stickfighting Days"" 
  2. "Sierra Leone's Olufemi Terry wins Caine writing prize". BBC News (BBC). 6 July 2010. http://news.bbc.co.uk/2/hi/world/africa/10519045.stm. Retrieved 6 July 2010. 
  3. 3.0 3.1 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named Sierra Leone's Olufemi Terry wins Caine writing prize2
  4. 4.0 4.1 4.2 "African literary prize goes to Cape Town writer". CBC News. 6 July 2010. http://www.cbc.ca/arts/books/story/2010/07/06/caine-prize-african-writing.html?ref=rss. Retrieved 6 July 2010. 
  5. Ogunlesi, Tolu (7 July 2010). "Olufemi Terry wins 2010 Caine Prize for African Writing". NEXT. http://234next.com/csp/cms/sites/Next/ArtsandCulture/5590567-147/story.csp. Retrieved 7 July 2010. 
  6. Frenette, Brad (6 July 2010). "Olufemi Terry wins 2010 Caine Prize". National Post (Canwest). http://arts.nationalpost.com/2010/07/06/olufemi-terry-wins-caine-prize/. Retrieved 6 July 2010. 
  7. Flood, Alison (6 July 2010). "Olufemi Terry wins Caine prize for African writing". The Guardian (London). https://www.theguardian.com/books/2010/jul/06/olufemi-terry-wins-caine-prize.