Patrick Seubo Koshoni
Olóṣèlú
Patrick Seubo Koshoni tàbí Patrick Sẹ́húbò Koshoni tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù kẹrin ọdún 1943 tí ó sìn kú ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù kìíní ọdún 2020 (April 17, 1943- 25 January, 2020) jẹ́ ajagun-fẹ̀yntì orí omi Nigerian Navy Vice Admiral,[1] ọ̀gágun yányán Chief of Naval Staff àti mínísítà-ana fún ìlera nígbà ìṣèjọba ológun Ààrẹ Muhammadu Buhari.[2] [3] Nígbà ìṣèjọba rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí mínísítà-ana fún ètò ìlera, ó gbìyànjú láti ṣe ìdásẹ̀lé ètò Máàdámidófò lórí ìlera láìsí owó sísan kalẹ̀
Chief of Naval Staff | |
---|---|
In office 1986–1990 | |
Asíwájú | Rear Adm. A. Aikhomu |
Arọ́pò | Vice Adm. M. Nyako |
Federal Minister of Employment, Labour and Productivity | |
In office 1985–1986 | |
Federal Minister of Health | |
In office December 1983 – August 1985 | |
Asíwájú | D.C Ugwu |
Arọ́pò | Olikoye Ransome-Kuti |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Lagos | Oṣù Kẹrin 17, 1943
Aláìsí | January 25, 2020 | (ọmọ ọdún 76)
Alma mater | St Finbarr's College National Defence Academy |
Military service | |
Allegiance | Nigeria |
Branch/service | Nigerian Navy |
Years of service | 1962-1990 |
Rank | Vice Admiral |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Business Report | Get The Latest South African Business News". www.iol.co.za (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-01-31.
- ↑ Francis Arthur Nzeribe (1985). Nigeria, another hope betrayed: the second comìing of the Nigerian military. Kilimanjaro. p. 117. https://books.google.com/books?ei=A5IeTJX6OOSKnwf4_YXNCw&ct=result&id=kXMuAQAAIAAJ&dq=Patrick+Koshoni+health&q=Patrick+Koshoni#search_anchor. Retrieved 2010-06-20.
- ↑ "KOSHONI, Vice-Admiral Patrick Seubo (rtd.)". Biographical Legacy and Research Foundation. 2017-03-02. Retrieved 2020-02-02.