Peter "Pete" Sampras ( /ˈsæmprəs/; ojoibi August 12, 1971) ni ara Amerika to ungba tenis to ti feyinti ati eni ipo No. 1 Lagbaye tele. Nigba odun 14 to fi gba tenis ATP, o gba ife-eye Grand Slam 14 awon enikan besini o je gbigba bi ikan ninu awon agba tenis to lokiki julo lailai.[1]

Pete Sampras
Pete Sampras (2008) 1, cropped.jpg
Orílẹ̀-èdèÀdàkọ:U.S.
IbùgbéLake Sherwood, California
Ọjọ́ìbíOṣù Kẹjọ 12, 1971 (1971-08-12) (ọmọ ọdún 48)
Potomac, Maryland
Ìga1.85 m (6 ft 1 in)
Ìgbà tódi oníwọ̀fà1988
Ìgbà tó fẹ̀yìntì2002
Ọwọ́ ìgbáyòOwo otun (owo kan eyin-owo)
Ẹ̀bùn owó$43,280,489
Ilé àwọn Akọni2007 (member page)
Iye ìdíje762–222 (77.43%)
Iye ife-ẹ̀yẹ64
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 1 (April 12, 1993)
Open AustrálíàW (1994, 1997)
Open FránsìSF (1996)
WimbledonW (1993, 1994, 1995, 1997, 1998, 1999, 2000)
Open Amẹ́ríkàW (1990, 1993, 1995, 1996, 2002)
Ìdíje ATPW (1991, 1994, 1996, 1997, 1999)
Ìdíje Òlímpíkì3R (1992)
Iye ìdíje64–70 (47.76%)
Iye ife-ẹ̀yẹ2
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 27 (February 12, 1990)
Open Austrálíà2R (1989)
Open Fránsì2R (1989)
Wimbledon3R (1989)
Open Amẹ́ríkà1R (1988, 1989, 1990)
Last updated on: October 23, 2012.


ItokasiÀtúnṣe