Queen Moremi: The Musical
Queen Moremi: The Musical jẹ́ fíìmù ilẹ̀ Nàìjíríà ti ọdún 2018 tó dá lórí Mọ́remí Àjàsoro tí sẹ́ńtúrì kejìlá. Bolanle Austern-Peters Productions àti House of Oduduwa ló ṣe àgbéjáde fíìmù yìí, tí olùdarí eré sì jẹ́ Bolanle Austen-Peters, tí Joseph Umoibum ló sì ṣe é. Kehinde Oritinehin ló kọ orin náà.[1]
Ìgbéjáde
àtúnṣeÈrò nípa fíìmù yìí wáyé ní December 2017.[2] Ọmọọbabìnrin Ronke Ademiluyi ló tọ Austern-Peters láti jẹ́ olùarí fíìmù náà. [3]
Paolo Sisiano àti Justin Ezirin ló darí ijó inú eré náà.[4] House of Emisara ló sì pèsè ohun-ẹ̀ṣọ́ tí wọ́n lò.[5]
Ìṣàfihàn àkọ́kọ́ wáyé ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kejìlá, ọdún 2018, títí wọ ọjọ́ kejì osù kìíní, ọdún 2019 ní Terra Kulture Arena, ní Victoria Island.[6][7][8]
Ní oṣù kẹrin, ọdún 2019, wọ́n ṣàfihàn ẹ̀yà mìíràn ní Èkó, láti ọjọ́ kẹjìdínlógún oṣù kẹrin wọ ọjọ́ karùn-ún oṣù karùn-ún ọdún 2019 bákan náà.[9] Wọ́n tún ṣàfihàn eré náà ní ẹlẹ́ẹ̀kẹta ní oṣù kejìlá láti ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kejìlá ọdún 2019 wọ ọjọ́ kejì oṣù kìíní ọdún 2020.[10][11]
Ìsọníṣókí
àtúnṣeÌtàn Moremi tó fìgbà kan jẹ́ olorì ilẹ̀ Yorùbá tó gba àwọn ará Ilé-Ifẹ̀ lọ́wọ́ àwọn Ugbo tó kó wọ́n lẹ́rú ni eré náà dá lórí.[12][13] Ó déjèé pẹ̀lú òrìṣàbìnrin ti odò Esinmirin láti lè ṣẹ́gun awọn ọ̀tá wọn. Ọwọ́ àwọn Ugbo tẹ̀ ẹ́, ó sì mọ àṣírí wọn kí ó tó padà lọ sí Ilé-Ifẹ̀. Ó darí ogun láti dokú ìjà kọ àwọn Ugbo, ó sì borí wọn. Esinmirin bẹ Moremi wò, ó sì bèrè fún "ohun tó ṣe pàtàkì si jù lọ".[14]
Àwọn akópa
àtúnṣeRole | 2018-2019 Run | Reloaded: December 2019 |
---|---|---|
Queen Moremi | Tosin Adeyemi, Kehinde Bankole, Omotola Jalade-Ekehinde | |
Obalufen | Deyemi Okanlawon | |
Olugbo | Femi Branch[15] | |
Oranmiyan | Rotimi Adelegan | Ademiluyi Adelegan[16] |
Esimirin | Lala Akindoju[15][17] | Mojisola Kadiri[16][18] |
Alaiyemore | Toyin Oshinaike[18] | |
Omoremi | Princess Obuseh, Oluwafeyikemi Agbola[18] | |
Bamike Olawunmi | ||
Bimbo Manuel |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "The making of Moremi The Musical". The Guardian Nigeria News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-04-21. Archived from the original on 2022-07-29. Retrieved 2022-07-29.
- ↑ "Moremi the Musical goes to US, Europe". The Guardian Nigeria News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-01-05. Archived from the original on 2023-01-28. Retrieved 2023-01-28.
- ↑ Empty citation (help)
- ↑ Ugobude, Franklin (2019-07-27). ""Queen Moremi The Musical": Immortalizing a Traditional Legend". The Theatre Times (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-01-28.
- ↑ Empty citation (help)
- ↑ "The Premiere Of Queen Moremi The Musical". The Guardian Nigeria News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-12-17. Archived from the original on 2022-07-29. Retrieved 2022-07-29.
- ↑ "In Queen Moremi the Musical, BAP, House of Oduduwa tell Yoruba heritage's tale". The Guardian Nigeria News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-11-18. Archived from the original on 2020-12-18. Retrieved 2022-07-29.
- ↑ Onyeakagbu, Adaobi (2018-11-27). "Queen Moremi 'The Musical': Anticipate the gripping story behind one of Yoruba's greatest queens". Pulse Nigeria. Retrieved 2022-07-29.
- ↑ Anazia, Daniel (2019-04-20). "Queen Moremi The Musical returns to stage in Lagos". The Guardian Nigeria News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-01-28.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Moremi the Musical: The story of an 'African feminist' queen". The Nation Newspaper (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-12-11. Retrieved 2022-07-29.
- ↑ Mgbeahuru, Ransome (2019-12-04). "Queen Moremi The Musical returns to Lagos for Yuletide". The Guardian Nigeria News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2023-01-28. Retrieved 2023-01-28.
- ↑ "The making of Moremi The Musical". The Guardian Nigeria News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-04-21. Archived from the original on 2022-07-29. Retrieved 2022-07-29.
- ↑ Onyeakagbu, Adaobi (2022-06-21). "Queen Moremi: Did you know about the courageous legend whose statue is the tallest in Nigeria?". Pulse Nigeria. Retrieved 2022-07-29.
- ↑ Tayo, Ayomide O. (2018-12-24). "Queen Moremi: The Musical, an ancient story that is perfect for these times". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-05-10.
- ↑ 15.0 15.1 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:3
- ↑ 16.0 16.1 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:4
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:5
- ↑ 18.0 18.1 18.2 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:6