Rẹ̀mí Babalọlá

Olóṣèlú

Adérẹ̀mí W. Babalọlá jẹ́ Mínísítà Ìpínlẹ̀ fún Ètò Ìṣúná ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà [1] láti 9jọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù keje ọdún 2007 sí ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹsàán ọdún 2010. Rẹ̀mí jẹ́ òṣìṣẹ́ ilé-ìfowópamọ́, ó kọ̀wé fiṣẹ́ sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Mínísíta ètò ìṣúná látàrí awuyewuye tí ó jẹyọ lórí ọ̀rọ̀ tí ó s9 wípé àwọn kan ń ràgà bo state epo rọ̀bì ilẹ̀ Nàìjíríà [2][3] Ní oṣù Kẹwàá ọdún 2008, Rẹ̀mí ọ́n yan gègẹ́ bí Mínísítà alámòójútó fún olú Ìlú Àbújá láfikún sí ipò tí ó wà gẹ́gẹ́ bí Mínísítà fún ètò ìṣúná, tí ó sì lo ipò náà títí di ìparí ọdún 2008. [citation needed] Ní kété sí ó sọ nípa ìjẹ gàba lé epo rọ̀bì orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni wọ́n yọ kúrò ní ipò Mínísítà fún ètò ìṣúná tí wọ́n sì fi sí ìdí àwọn iṣẹ́ àkànṣe kan ní ní inú ìgbìmọ̀ Mínísítà, èyí ló mu tí ó fi kọ́wé fi ipò rẹ̀ sílẹ̀ kúró gẹ́gẹ́ bí Mínísítà fún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí ó sì tún kọ̀ láti gba iṣẹ́ àkànṣe tí wọ́n fún n. [4]

Gẹ́gẹ́ bí onímọ̀ nípa ẹ̀rọ “technocrat”,[5] Ní àsìkò tí Rẹ̀mí di Mínísítà, ó hùwà òtítọ́ inú gẹ́gẹ́ bí ó ṣe jẹ́ Mínísítà àkọ́kọ́ tí yóò kéde gbogbo ohun ìní rẹ̀ fárá gbọ́ ní àsìkò ìṣèjọba Ààrẹ ànọ́ Remi's stint in public office was marked by a concern with transparency that began with him being one of the first ranking federal government officials in the Umar Yar'Adua ní ọdún (2007/2011)[citation needed]. Ṣáájú ìyànsípò rẹ̀, òun ni adarí ilé ìfowó-pamọ́ ti First Bank of Nigeria Limited[citation needed]. Bákan náà ni ó ti ṣe alákòóso àgbà fún.ilé ìfowó-pamọ́ ti Zenith Bank Nigeria Plc., àti àwon akitiyan rẹ̀ lórí àgbéyẹwò, ìdánilẹ́kọ̀ọ́ àti ìyaṣẹ́ fúni ní àwọn ilé ìfowó-pamọ́ tí ó ti ṣiṣẹ́. Ní ọdún 2009, Rẹ̀mí fi iye owó ó tó mílíọ́nù kan Dọ́là kọ́ ilé-ìwòsan tí a mọ̀ sí Rẹ̀mí Babalọlá Red Cross Mediacl Centre sí ìlú Ìbàdàn fún àwọn òṣìṣẹ́ Red Cross ti ẹkùn Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Ilé-ìwòsan náà sì ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí ilé-ìwòsan lẹ́sẹ̀ kùkú ní ìlú Ìbàdàn.[citation needed]. Rẹ̀mí kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní inú ìmọ̀ okòwò àgbẹ̀ láti fáfitì Ìlú Ìbàdàn, ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Institute of Chartered Accountants of Nigeria, the Chartered Institute of Taxation of Nigeria,àti the Institute of Directors of Nigeria. Ó tún ní ìwé ẹ̀rí ìmọ̀ kejì (Masters) nínú ìmọ̀ ìfowó-pamọ́ àti ìṣúná láti Fáfitì Ìlú Èkó.[citation needed]

Àwọn Ìtọ́ka sí

àtúnṣe
  1. "Honorable Minister of State for Finance". Nigerian Federal Ministry of Finance. Archived from the original on 19 February 2010. 
  2. "Nigeria state oil firm NNPC insolvent, says minister". www.bbc.com. BBC. Retrieved 3 February 2015. 
  3. "NNPC Is Bankrupt - Babalola". www.pmnewsnigeria.com. PM News. Retrieved 3 February 2015. 
  4. "Minister Of State For Finance, Remi Babalola, Moved To Special Duties". www.saharareporters.com. Sahara Reporters. 
  5. Oronsaye, Stanley (17 September 2010). Babalola; a technocrat bows out "Remi Babalola; a technocrat bows out" Check |url= value (help). www.proshareng.com. Proshare Nigeria. 

Àwọn.Ìtàkùn ìjá sóde

àtúnṣe


Àdàkọ:Nigeria-politician-stub