Rafael Nadal
Rafael "Rafa" Nadal Parera (Catalan: [rəˈfɛɫ nəˈðaɫ pəˈɾeɾə]; Spanish: [rafaˈel naˈðal paˈɾeɾa]) (ojoibi 3 June 1986) je omo Spani agba tenis alagbase to wa ni ipo kinni lagbaye. Nadal ti gba ife eye awon enikan Grand Slam mejo, eso wura 2008 Olympiki fun awon enikan, o ni record 18 fun awon idije ATP World Tour Masters 1000 o si tun je ara egbe Ife Eye Davis Spein to bori opin idije ni 2004, 2008 ati 2009. O je gbigba bi ikan ninu awon agba tenis to lokiki julo laye.
Nadal in 2016 | ||||||||||||||
Orúkọ | Rafael Nadal Parera | |||||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Orílẹ̀-èdè | Spéìn | |||||||||||||
Ibùgbé | Manacor, Balearic Islands, Spain | |||||||||||||
Ọjọ́ìbí | 3 Oṣù Kẹfà 1986 Manacor, Balearic Islands, Spain | |||||||||||||
Ìga | 1.85 m (6 ft 1 in) | |||||||||||||
Ìgbà tódi oníwọ̀fà | 2001 | |||||||||||||
Ọwọ́ ìgbáyò | Left-handed (two-handed backhand), born right-handed | |||||||||||||
Olùkọ́ni | Toni Nadal (1990–2017)[1] Francisco Roig (2005–)[2] Carlos Moyá (2016–)[3] | |||||||||||||
Ẹ̀bùn owó | US$90,641,902 | |||||||||||||
Ojúewé Íntánẹ́ẹ̀tì | rafaelnadal.com | |||||||||||||
Ẹnìkan | ||||||||||||||
Iye ìdíje | 867–183 (82.57%) | |||||||||||||
Iye ife-ẹ̀yẹ | 75 (5th in the Open Era) | |||||||||||||
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 1 (18 August 2008) | |||||||||||||
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ | No. 1 (25 September 2017) | |||||||||||||
Grand Slam Singles results | ||||||||||||||
Open Austrálíà | W (2009) | |||||||||||||
Open Fránsì | W (2005, 2006, 2007, 2008, 2010, 2011, 2012, 2013, 2014, 2017) | |||||||||||||
Wimbledon | W (2008, 2010) | |||||||||||||
Open Amẹ́ríkà | W (2010, 2013, 2017) | |||||||||||||
Àwọn ìdíje míràn | ||||||||||||||
Ìdíje ATP | F (2010, 2013) | |||||||||||||
Ìdíje Òlímpíkì | W (2008) | |||||||||||||
Ẹniméjì | ||||||||||||||
Iye ìdíje | 131–72 | |||||||||||||
Iye ife-ẹ̀yẹ | 11 | |||||||||||||
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 26 (8 August 2005) | |||||||||||||
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ | No. 560 (9 October 2017)[4] | |||||||||||||
Grand Slam Doubles results | ||||||||||||||
Open Austrálíà | 3R (2004, 2005) | |||||||||||||
Wimbledon | 2R (2005) | |||||||||||||
Open Amẹ́ríkà | SF (2004) | |||||||||||||
Àwọn ìdíje Ẹniméjì míràn | ||||||||||||||
Ìdíje Òlímpíkì | W (2016) | |||||||||||||
Àwọn Ìdíje Ẹgbẹ́ Agbáyò | ||||||||||||||
Davis Cup | W (2004, 2008, 2009, 2011) | |||||||||||||
Iye ẹ̀ṣọ́
| ||||||||||||||
Last updated on: Àdàkọ:Date. |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "Report: Toni Nadal to stop traveling with Rafa at the end of '17".
- ↑ "Francisco Roig: “In Some Ways, This Is Our Biggest Goal” - ATP World Tour - Tennis". atpworldtour.com. Retrieved 10 September 2017.
- ↑ "Rafael Nadal hires Carlos Moya as he bids to revive injury-hit careeer". CNN. 17 December 2016. Retrieved 19 December 2016.
- ↑ "ATP World Tour – Rafael Nadal Profile". ATP Tour. Retrieved 16 August 2016.