Reminisce
Reminisce (Alaga Ibile) jẹ́ ọmọ bíbí ilẹ̀ Ajilete, ìbílẹ̀ gúúsù Yewa ní ìpínlẹ̀ Ogun, apá ìwọ̀ oòrùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Wọ́n bí i ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù ṣẹẹrẹ ọdún 1981, ní ìpínlẹ̀ Kaduna, apá àríwá orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Reminisce | |
---|---|
Orúkọ àbísọ | Remilekun Abdulkalid Safaru |
Ọjọ́ìbí | 26 Oṣù Kínní 1981 Kaduna, Nigeria |
Irú orin | |
Occupation(s) | Singer, rapper, song-writer, Record Label Owner,actor |
Years active | 2008–present |
Labels | LRR Records |
Associated acts |
|
A bí Rẹ̀mílẹ́kún Khàlid Sàfárù ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù ṣẹẹrẹ, orúkọ mìíràn tí arákùnrin yìí ń jẹ́ ni orí-ìtàgé ni Reminisce àti Alága ìbílẹ̀. Ó jẹ́ olórin tàka-súfèé ti ilè Nàìjíríà, bẹ́ẹ̀ náà ni ó jẹ́ òǹkọrin àti eléré tíátà láti ìpínlẹ̀ Ògùn. Ògbóǹtarìgì ni ó jẹ́ nínú fífí èdè Gèésì àti èdè abínibí rẹ̀ Yorùbá[1][2] dánilárayá.
Ìfáàrà
àtúnṣeReminisce (Alaga Ibile) jẹ́ ọmọ bíbí ilẹ̀ Ajilete, ìbílẹ̀ gúúsù Yewa ní ìpínlẹ̀ Ogun, apá ìwọ̀ oòrùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Wọ́n bí i ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù ṣẹẹrẹ ọdún 1981, ní ìpínlẹ̀ Kaduna, apá àríwá orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Nígbà tí ó wà ní ilé ìwé, oríṣiríṣi àwọn orin tàka-súfèé tí orílè-èdè Nàìjíríà àti ti òkè-òkun ni ó máá ń gbọ́, ó sì máa ń kọ àwọn orin yìí ní orí-ìtàgé nígbàkugbà tí ilé-ìwé rẹ̀ bá ń ṣe síse. Ó mú ìdàgbàsókè bá ẹ̀bùn orin kíkọ rẹ̀ nípa gbígbọ́ orin àwọn olórin tàka-súfèé mìíràn bí i Nas, Jay z àti Snoop Dogg. Ilé- ẹ̀kọ́ gíga pólì ni ó ti ka kárà-kátà ( purchasing and supply).
Iṣẹ́ nínú orin kíkọ
àtúnṣeỌdún 2006 ní ó se àkójọ àwọ rẹ̀ àkọ́kọ́ ní ilé-iṣẹ́ Coded Tunes, àmọ́ àwo yìí kò jáde. Fún ìdí èyí, ó gbájúmọ́ ẹ̀kọ́ àtí píparí ẹ̀kọ́ rẹ̀. Ní ọdún 2008, ó padà sí ori kíkọ. Lára àwọn orin tí ó sọ ọ́ di ìlú mọ̀ọ́ká ni: Bachelor's Life tí ó kọ pẹ̀lú 9ice, àti If Only tí Dtunez gbé jáde.
Ilé-iṣẹ́ Edge Records gbà á láti máa ṣiṣẹ́ fún wọn, bẹ́ẹ̀ náà ni ó jẹ́ olùdásílẹ̀ àti olùdaeí ilé-iṣẹ́ LRR Records. Ní ọdún 2014, TIME Magazine pe REMINISCE ní (ọ̀kan nínú àwọn olórin tàka-súfèé méje tí o gbọ́dọ̀ rí) “one of the seven World Rappers You Should Meet”[3] Ọ̀kan lára àwọn ayélujára fún orin pè é ni NOTJUSTOK, gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan nínú àwọn olórin tàka-súfèé mẹ́ta tí ó mú òkè ní ọdún 2014. [4] Àwo rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ "Local Rappers" tí ó gbé jáde ní ọdún 2015, èyí tí ó kọ pèlú Olamide àti Phyno mú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àrínyàngiyàn dání pé àwọn tí wọ́n fi èdè Gẹ̀ẹ́sì kọrin ní ó báwí bí i MI àti Mode9.[5]
Àwọn orin rẹ̀
àtúnṣeÀwo-orin
àtúnṣeOrin àdákọ
àtúnṣe- One Chance[9]
- Ever Since ft 9ice[6]
- If Only[10]
- Kako Bii Chicken[11]
- 2musshh[12]
- Fantasi[13]
- Government ft Olamide, Endia[14]
- Daddy ft Davido[15]
- Eleniyan ft Wizkid[16]
- Turn It Around[17]
- Tesojue[18]
- "Local Rappers"
- Skilashi
- Kpomo (Remix) Feat. Lil. Kesh, CDQ, Falz, Seriki[19]
- Angelina [20]
- Ponmile (2017)
- Problem (2018)
- Ajigijaga (2018)
- Do You Feel It (2018)
- Oja (2019)
- Jensimi (featuring Niniola (2019)
- Instagram[21] (featuring Olamide, Naira Marley, Sarz (2019)
- Prosperity (featuring Falz ) (2020)
- Toxic[22] (featuringAdekunle Gold (2020)
Videography
àtúnṣeYear | Title | Album | Director | Ref |
---|---|---|---|---|
2016 | style="background: #ececec; color: grey; vertical-align: middle; text-align: center; " class="table-na" | N/A|style="background: #ececec; color: grey; vertical-align: middle; text-align: center; " class="table-na" | N/A | [23] |
Orin àjọkọ
àtúnṣe- ASHEWO Performed by Phenom (2013)
- SHEKPE Performed by M.I (2014)
- KING KONG [REMIX] Performed by Vector (2015)
- 69 Missed Call Ft Jahbless, Chinko Ekun, Lil Kesh, Olamide, CDQ, Reminisce
- Ibile performed by Lil Kesh (2016)
- If E No Be God performed by Mr Eazi
- Diet by Dj Enimoney (2018)
- Aye by CDQ (2018)
- Original Gangstar by Sess (2018)
Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Reminisce Full Bio". Jango.com. Jango. Retrieved 12 May 2015.
- ↑ "Reminisce Biography: Age, Early Life, Education, Family, Career, Collaborations, Awards, Controversy, Endorsements". NAIJAlebrity (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-01-08. Retrieved 2021-01-05.
- ↑ Video, Time (12 July 2014). "Forget Eminem: World Rappers You Should Meet". http://time.com/2977682/forget-eminem-world-rappers-you-should-meet/. Retrieved 4 June 2015.
- ↑ "Reminisce". Last.fm. Last.fm. Retrieved 12 May 2015.
- ↑ "I have no beef with Reminisce, others on local rappers — Modenine". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-09-18. Retrieved 2021-02-26.
- ↑ 6.0 6.1 "Book of Rap Songs". 360nobs. 360nobs. Archived from the original on 6 November 2014. Retrieved 12 May 2015.
- ↑ "Album Review". The Net. The Net. Retrieved 12 May 2015.
- ↑ "Reminisce releases 3rd album". Jaguda. Jaguda. Archived from the original on 4 May 2015. Retrieved 12 May 2015.
- ↑ "One Chance". Vod. Vod. Archived from the original on 10 August 2014. Retrieved 12 May 2015.
- ↑ "If Only". Not Just OK. Not Just OK. Archived from the original on 18 May 2015. Retrieved 12 May 2015.
- ↑ "Kill Bii Chicken". Not Just OK. Not Just OK. Archived from the original on 18 May 2015. Retrieved 12 May 2015.
- ↑ "2mussh". Jaguda. Jaguda. Archived from the original on 18 May 2015. Retrieved 12 May 2015.
- ↑ "Fantasi". Not Just OK. Not Just OK. Archived from the original on 18 May 2015. Retrieved 12 May 2015.
- ↑ "Government". Ace World Team. Ace World Team. Retrieved 12 May 2015.
- ↑ "daddy". MTV Base. MTV Base. Retrieved 12 May 2015.
- ↑ "Eleniyan". Not Just OK. Not Just OK. Archived from the original on 9 May 2015. Retrieved 12 May 2015.
- ↑ "turnit". MTV Base. MTV Base. Retrieved 12 May 2015.
- ↑ Youtube, Reminisce. "Reminisce - Tesojue [Explicit Video]". Youtube. Youtube. Retrieved 4 December 2014.
- ↑ "Kpomo (Remix)". Pulse.ng. Joey Akan. Archived from the original on 5 December 2015. Retrieved 4 December 2015.
- ↑ "New Music Reminisce - 'Angelina'". Pulse,ng. Joey Akan. Archived from the original on 28 January 2016. Retrieved 26 January 2016.
- ↑ "Reminisce Ft. Olamide, Naira Marley, Sarz – 'Instagram'". LocaaTunes - Much Xclusive Music. December 10, 2019. Retrieved December 9, 2020.
- ↑ "Reminisce x Adekunle Gold – 'Toxic'". LocaaTunes - Much Xclusive Music. December 9, 2020. Archived from the original on December 9, 2020. Retrieved December 9, 2020.
- ↑ "Reminisce Rapper falls in love in colourful 'Angelina' video". Pulse.ng. Joey Akan. Archived from the original on 28 January 2016. Retrieved 26 January 2016.