Rhythm 93.7 FM Port Harcourt

Rhythm 93.7 FM jẹ́ rédíò ti iṣowo tí ó wà ní agbègbè Old GRA ti Port Harcourt, Ìpínlẹ̀ Rivers. Ilé iṣẹ́ rédíò yìí á máa ṣe àwọn ìkéde òde òní, wọ́n a máa gbé orin onírúurú síi bíi R&B, hip hop, pẹ̀lú orin-ijó lẹ́ẹ̀kọ̀ọ̀kan àti reggae . O jẹ ohun ini ati ẹ̀ka ìṣiṣẹ́ Silverbird Communications lábẹ́ ilé-iṣẹ́ Silverbird Group àti pé ó jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ilé-iṣẹ rédíò aládàáni tí ó lókìkí jùlọ ní ìhà gúúsù orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Ètò Ago
Afternoon drive Monday - Friday 2:00 PM - 4:00 PM
Dance Party Monday - Friday (ayafi Thursday) 7:30 PM - 10:00 PM
Gospel Vibes Sunday 8:00 AM - 10:00 AM
Late Night caller Tuesdays 10:00 PM - 12 AM
Launch Box Oldies Monday - Sunday 12:15 PM - 2:00 PM
Mo Fire Wednesdays 8:00 PM - 10:00 PM
Morning Drive Monday - Friday 6:00 AM - 10:00 AM
Rap Culture Saturday 6:30 PM - 8:00 PM
Rhythm & Soul Monday - Friday 10:00 AM - 12:00 PM
Rhythm of the Night Mondays 10:00 PM - 12:00 AM
Showout Show Saturday 2:00 PM - 4:00 PM
Sunday at the Rhythm Sunday 2:00 PM - 4:00 PM
Shoutout show Saturday 8:00 AM - 9:15 AM
The TGIF Chart Ọjọ Jimọ 9:00 Ọ̀sán - 10:00 Ọ̀sán

Òṣìṣẹ́

àtúnṣe

Dísíkí Jokì

àtúnṣe
  • DJ best
  • DJ Spin
  • DJ DoubleD
  • DJ Golden

DJ Tan

Àwọn Olóòtú

àtúnṣe
  • Azubuike Wokocha
  • Stephanie Obuzo
  • Chikodi Nwosu
  • Charlse Baridam
  • Ben Wakama

Àwọn òṣìṣẹ́ orí afẹ́fẹ́ tẹ́lẹ̀

àtúnṣe
  • Andre Blaze, ṣiṣẹ́ Lọ́wọ́lọ́wọ́ ní The Virtuoso Company
  • Ifeoma Iphie Aggrey-Fynn (ó kú 2015)
  • Cleopatra Tawo, ó wà pẹ̀lú Planet FM 101.1 ni Uyo báyìí

Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀

àtúnṣe

Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ òfin

àtúnṣe

Ní ọjọ́ kọkànlá Oṣù Kejìlá ọdún 2005, méjì nínú àwọn Olóòtú rédíò Klem Ofuokwu àti Cleopatra Tawo ni wọ́n mú tí wọ́n sì fẹ̀sùn kàn pé wọ́n sọ ìròyìn irọ́ nípa ìkùnà Afárá. Wọ́n fi wọ́n sẹ́wọ̀n fún ọ̀sẹ̀ méjì, lẹ́yìn náà ni wọ́n dá wọn sílẹ̀ lórí ẹ̀wọ̀n.

Wo eléyìí náà

àtúnṣe
  • Orin ti Port Harcourt
  • Àtòjọ àwọn ilé-iṣẹ́ rédíò ní Port Harcourt

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe

Ita ìjápọ

àtúnṣe