Rodney George "Rod" Laver MBE (ojoibi 9 August 1938) je agba tennis ara Australia to ni akosile fun gbigba ife-eye topojulo ninu tenis pelu ife-eye idije 200 ati to gba awon ife eye Grand Slam.

Rod Laver
Oṣere tẹnisi ọmọ ìlú Ọstrelia, Rod Laver ni ọdún 1969 ní àkókò Top Tennis Figagbaga ni Amsterdam
Orílẹ̀-èdè Australia
IbùgbéCarlsbad, California, United States
Ọjọ́ìbí9 Oṣù Kẹjọ 1938 (1938-08-09) (ọmọ ọdún 86)
Rockhampton, Queensland, Australia
Ìga1.73 m (5 ft 8 in)
Ìgbà tódi oníwọ̀fà1963
Ìgbà tó fẹ̀yìntì1976
Ọwọ́ ìgbáyòLeft-handed (one-handed backhand)
Ẹ̀bùn owó$1,565,413
Ilé àwọn Akọni1981 (member page)
Ẹnìkan
Iye ìdíje411–107 (79.34% in Open Era)
Iye ife-ẹ̀yẹ200 (41 listed by the ATP Website)
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 1 (1961, Lance Tingay)[1]
Grand Slam Singles results
Open AustrálíàW (1960, 1962, 1969)
Open FránsìW (1962, 1969)
WimbledonW (1961, 1962, 1968, 1969)
Open Amẹ́ríkàW (1962, 1969)
Àwọn ìdíje míràn
Ìdíje ATPRR – 2nd (1970)
WCT FinalsF (1971, 1972)
Professional majors
US ProW (1964, 1966, 1967)
Wembley ProW (1964, 1965, 1966, 1967)
French ProW (1967)
Ẹniméjì
Iye ìdíje235–77 (75.32%)
Iye ife-ẹ̀yẹ28
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 11
(all as recorded by the ATP)
Last updated on: August 13, 2012 by Asmazif.


  1. United States Lawn Tennis Association (1972). Official Encyclopedia of Tennis (First Edition), p. 427.