Saka Abimbola Isau SAN jẹ ọmọ orile-ede Nàìjíríà ati olóṣèlú to je akọ̀wé fun ìjọba ìpínlè, Komisana fun Ìdájọ́ ati Attorney General ti Ìpínlè Kwara ni àkókò ti Bukola Saraki . [1] [2] [3]

Saka Isau
Attorney General and Commissioner of Justice
In office
4 September 2003 – 23 March 2011
SSG to Kwara State
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Saka Abimbola Isau

1956
Aláìsí4 January 2025
Ilorin, Kwara State

Isau je ọmọ ẹgbẹ́ People's Democratic Party, o si dije fun tikeeti gomina egbe naa ninu idibo gbogbogbòò odun 2019, pelu Bolaji Abdullahi . [4] [5] O ṣiṣẹ gẹgẹbi alága 14th ti Nigerian Bar Association ti eka Ilorin láàrin ọdún 2000 - 2001. [6]

Awọn itọkasi

àtúnṣe