Sofia Kenin
Sofia Anna Kenin[1] (pẹ̀lú ìnagijẹ Sonya, /ˈsoʊniə ˈkɛnɪn/ SOH-nee-ə-_-KEN;[2] ọjọ́ìbí November 14, 1998) ni agbá tẹ́nìs ará Amẹ́ríkà. Ipò rẹ̀ tógajùlọ láàgbáyé àjọ Women's Tennis Association (WTA) ni No. 4. Kenin gba ife-ẹ̀yẹ Open Australi 2020 nígbà tó borí Garbine Muguruza ní ìparí ìdúje náà, èyì sọ ọ́ di ọ̀dọ́mọdé kékeré jùlọ ará Amẹ́ríkà tó gba ìdíje Grand Slam àwọn ọbìnrin ẹnìkan lẹ́yìn Serena Williams ní 2002.
Kenin at the 2019 French Open | |
Orílẹ̀-èdè | USA |
---|---|
Ibùgbé | Pembroke Pines, Florida, US |
Ọjọ́ìbí | 14 Oṣù Kọkànlá 1998 Moscow, Russia |
Ìga | 1.70 m (5 ft 7 in) |
Ìgbà tódi oníwọ̀fà | 2017 |
Ọwọ́ ìgbáyò | Right-handed (two-handed backhand) |
Olùkọ́ni | Alex Kenin |
Ẹ̀bùn owó | US$ 5,930,775 |
Ojúewé Íntánẹ́ẹ̀tì | sonyakenin.com |
Ẹnìkan | |
Iye ìdíje | 205–116 (63.86%) |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 5 |
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 4 (March 9, 2020) |
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ | No. 4 (March 9, 2020) |
Grand Slam Singles results | |
Open Austrálíà | W (2020) |
Open Fránsì | 4R (2019) |
Wimbledon | 2R (2018, 2019) |
Open Amẹ́ríkà | 3R (2017, 2018, 2019) |
Àwọn ìdíje míràn | |
Ìdíje WTA | RR (2019) |
Ẹniméjì | |
Iye ìdíje | 56–45 (55.45%) |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 2 |
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 32 (March 2, 2020) |
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ | No. 32 (March 9, 2020) |
Grand Slam Doubles results | |
Open Austrálíà | 3R (2020) |
Open Fránsì | 2R (2019) |
Wimbledon | 2R (2018) |
Open Amẹ́ríkà | 1R (2018, 2019) |
Àwọn Ìdíje Ẹgbẹ́ Agbáyò | |
Fed Cup | F (2018) |
Last updated on: Àdàkọ:Date. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "Sonya Kenin Biography". Sonya Kenin. Retrieved 6 March 2020.
- ↑ "Sofia Kenin, una tenista lista para el profesionalismo". VamosDeportes. 22 December 2014. Retrieved 3 January 2018.