Wives on Strike
Wives on Strike jẹ fiimu Naijiria ti ọdun 2016 ti Omoni Oboli ṣe ode tun je oludari. <a href="https://en.wikipedia.org/wiki/Uche_Jombo" rel="mw:ExtLink" title="Uche Jombo" class="cx-link" data-linkid="54">Uche Jombo</a>, Chioma Akpotha, Ufuoma McDermott, ati Kehinde Bankole wa lara awon osere to kopa ninu ere na.[1]
Awon Osere
àtúnṣe- <a href="https://en.wikipedia.org/wiki/Uche_Jombo" rel="mw:ExtLink" title="Uche Jombo" class="cx-link" data-linkid="61">Uche Jombo</a>
- Chioma Akpotha
- Ufuoma McDermott
- Kehinde Bankole
- <a href="https://en.wikipedia.org/wiki/Kalu_Ikeagwu" rel="mw:ExtLink" title="Kalu Ikeagwu" class="cx-link" data-linkid="69">Kalu Ikeagwu</a>
- Julius Agwu
- Kenneth Okonkwo
- Sola Sobowale
Ahunpo Itan
àtúnṣeAwon egbe obinrin ọja kan ti wọn kọ gba ki oko won bawon lajosepo, won feeyi fimo sokan lati duro fun odomobinrin kekere kan, ti baba rẹ fi agbara mu lati fẹ ọkunrin kan laisi ifẹ inu rẹ. A ya fiimu naa nigba ibara eni soro (Omo kiise Ayaa) #ChildNotBride beesile lawujo.[2]
Gbigbawọle
àtúnṣeIrede Abumere osise ile-isew Pulse gbóríyìn fún ìtàn náà àti lílo ọ̀nà amúnikún-fún-ẹ̀rù tí wọ́n gbà nínú eré àwòkẹ́kọ̀ọ́ fún ṣíṣe àtúnṣe sí àwọn ọ̀rọ̀ tó le koko.[3]
Iwe irohin Tush ṣe iwọn rẹ ni 4/5, o si gnoriyin fun koko eko ati awon oro awujo ti won fi se afihan ninu fiimu na.[4]
Apoti ọfiisi(Box office)
àtúnṣeNigbati fiimu naa ti jade, a gbọ pe o se daada ju awon fiimu Naijiria ti o wa lori apoti ofiisi.[5]
Awọn itọkasi
àtúnṣe- "Wives on Strike". Nollywood Reinvented. 20 March 2017. Retrieved 28 November 2021.
- "Omoni Oboli, Chioma Chukwuka, Uche Jombo deny husbands sex in trailer [watch]". Pulse.ng. 26 February 2016. Archived from the original on 17 February 2024. Retrieved 28 November 2021.
- Abumere, Irede (April 5, 2016). ""Wives On Strike" - an infectious comedy addressing a bigger issue". Pulse. Archived from the original on 2018-02-21. Retrieved 2018-10-27.
- "Movie Review: Wives On Strike". Tushmagazine.com.ng. Archived from the original on 2016-10-14. Retrieved 2018-10-27.
- "Wives on Strike makes N60 million at box-office". Vanguarddngr.com. May 8, 2016. Retrieved 2018-10-27.
- ↑ "Wives on Strike". Nollywood Reinvented. 20 March 2017. Retrieved 28 November 2021.
- ↑ "Omoni Oboli, Chioma Chukwuka, Uche Jombo deny husbands sex in trailer [watch]". Pulse.ng. 26 February 2016. Archived from the original on 17 February 2024. Retrieved 28 November 2021.
- ↑ Abumere, Irede (April 5, 2016). ""Wives On Strike" - an infectious comedy addressing a bigger issue". Pulse. Archived from the original on 2018-02-21. Retrieved 2018-10-27.
- ↑ "Movie Review: Wives On Strike". Tushmagazine.com.ng. Archived from the original on 2016-10-14. Retrieved 2018-10-27.
- ↑ "Wives on Strike makes N60 million at box-office". Vanguarddngr.com. May 8, 2016. Retrieved 2018-10-27.