The Bridge jẹ́ fíìmù orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó jáde ní ọdún 2017, èyí tí Kunle Afolayan darí, tí ó sì ṣàtẹ̀jádé.[1][2]

The Bridge
AdaríKunle Afolayan
Olùgbékalẹ̀Lasun Ray Eyiwumi
Òǹkọ̀wéShola Dada
Àwọn òṣèréChidinma Ekile
Demoal Adedoyin
Tina Mba
Ayo Mogaji
Zack Orji
Bayo Salami
OrinAnu Afolayan
Kent Edunjobi
OlóòtúAdelaja Adebayo
Ilé-iṣẹ́ fíìmùLasun Ray Films
Déètì àgbéjáde
  • 2017 (2017)
Àkókò118 minutes
Orílẹ̀-èdèNigeria
ÈdèEnglish

Àhunpọ̀ ìtàn

àtúnṣe

Ọmọọba kan láti ìdílé ọlọ́ba pinnu láti fẹ́ ọmọbìnrin kan tó wá láti ìdílé ọlọ́lá, àmọ́ àwọn òbí ọmọbìnrin náà ò fọwọ́ si nítorí wọn ò kì í ṣe ẹ̀yà kan náà. Èyí sì mú kí àwọn méjèèjì lọ́ fẹ́ ara wọn lẹ́yìn àwọn òbí wọn. Èyí sì mú kí ọ̀pọ̀lọpọ̀ nǹkan máa dàrú fún wọn.[3][4][5]

Àwọn akópa

àtúnṣe

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "The Bridge | Netflix". www.netflix.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 19 October 2020. Retrieved 3 November 2019. 
  2. nollywoodreinvented (13 September 2019). "The Bridge". Nollywood REinvented (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 3 November 2019. 
  3. "5 things you should know about Kunle Afolayan's new movie". www.pulse.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 7 November 2017. Retrieved 3 November 2019. 
  4. "Review- The Bridge (2017)". diaryofamovielover.blogspot.com. Retrieved 3 November 2019. 
  5. "MM Review: 'The Bridge' Directed by Kunle Afolayan". MamaZeus (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 14 December 2017. Archived from the original on 5 March 2020. Retrieved 3 November 2019.