Ken Erics
Ekenedilichukwu Ugochukwu Eric Nwenweh, tí àlàjẹ́ rẹ̀ ń jẹ́ Ken Erics Ugo tàbí Ken Erics jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, orí ẹ̀rọ amóhù-máwòrán àti ọ̀kọrin, ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó di ìlú-mòọ́ká látàrí ipa rẹ̀ tí ó kó nínú eré sinimá kan tí àkòrí rẹ̀ ń jẹ́ The Illiterate eré tí òṣèrébìnrin Tonto Dikeh àti Yul Edochie ti kópa.[1]Ó sì tún jẹ́ ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Anabra.
Ken Erics | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Ekenedilichukwu Ugochukwu Eric Nwenweh 28 Oṣù Kejì 1985 Kano, Kano State, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Nnamdi Azikiwe University, Awka |
Iṣẹ́ | Actor, writer, producer, musician, politician |
Ìgbà iṣẹ́ | 2001–present |
Website | https://kenericsofficial.com/ |
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀
àtúnṣeEọ́n bí Eric ní Ìpínlẹ̀ Kano, ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù Kejì ọdún 1985.[2]. Ó jẹ́ ọmọ ẹ̀tà Igbo ní apá ìlà Oòrùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti Binta Mustapha Science ní Ìpínlẹ̀ Kano. Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ girama Dennis Memorial Grammar (DMGS) ní ìlú Onitsha, ní Ìpínlẹ̀ Anambra Erics ti nífẹ́ sí eré ṣiṣẹ́ láti ìgbà tí ó ti wà ní kékeré.[3] Ó lọ zí ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásitì Nnamdi Azikiwe ní ìlú Awka* ní Ìpínlẹ̀ Anambra tí ó sì kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ìmọ̀ eré-oníṣe.[4] Ó sì tún kẹ́kọ̀ọ́ gboyè kejì nínú ìmọ̀ eré oníṣẹ́ àti sinimá bákan náà.
Iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeEric bẹ̀rẹ̀ eré orí-ìtàgé ní inú ọdún 2001, níbi tí ó ti kópa nínú eré ‘Holy Prostitute’ eré tí Chris Ubani darí rẹ̀.[5] Ó bẹ̀rẹ̀ sí ní kópa wẹ́wẹ̀wẹ́ ní irí àwọn eré sinimá àgbéléeò ọlọ́kan-ò-jọkan, láìpẹ́, ipa rẹ̀ tí ó kó nínú tí àkọ́lénrẹ̀ ń jẹ́ Ugo, eré yí ni ó s9ọ́ di ààyò àwọn ènìyàn nínú àwọn eré rẹ̀ tí ó kù. [6]Èyí ni ó sì tún ṣí àwọn ọ̀nà ànfaní mìíràn fun nínú agbo Nollywood. As a writer, Erics first published work "Cell 2"[7]Ó ti di ìlú-mòọ́ká, wọ́n sì ti m lòó nínú àwọn eré orísiríṣi ati awọn àpilẹ̀kọ eré oníṣẹ́ gbogbo ní orí-ìtàgé àwọn àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gbogbo. Eric ma ń kọrin ní ìgbà míràn tí ó sì ma ń ta jìtá ati keyboard nínú orin rẹ̀.[8] Ó ti kọ àwọn orin ọlọ́kan-ò-jọkan fún àwọn sinimá àgbéléwò pẹ̀lú. Òun àti àwọn òṣèré jànkàn-jànkàn bíi: Ngozi Ezeonu, Yul Educhie, Desmond Eliot, Chinwetalu Agu, Regina Daniels àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Ní ọdún 2014, Eric gba amì-ẹ̀yẹ fún Òṣèré kúnrin amúgbá-lẹ́gbẹ̀ẹ́ tí ó peregedé jùlọ níbi ayẹyẹ amì-ẹ̀yẹ ti City People Entertainment Award[9]Ó tún gba amì-ẹ̀yẹ fún Òṣèré kùrin aléwájú tí ó peregedé jùlọ níbi ayẹyẹ ti Afrifimo Awards ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Ní ọdún 2015, ó gba amì-ẹ̀yẹ ti Òṣèrékùrin tí ó peregedé jùlọ níbi ayẹyẹ ti City People Entertainment Award.[10]
Ní ọdún 2017, Erics tún gba amì-ẹ̀yẹ ti City People Entertainment Awards 2017 fún Òṣèrékùrin tí ó peregedé jùlọ Ó sì gba amì-ẹ̀yẹ fún ti Golden Movie Awards ní ọdún 2018 gẹ́gẹ́ bí Òṣèrékùrin tí ó peregedé jùlọ.
Àwọn Amì-ẹ̀yẹ rẹ̀
àtúnṣeỌdún | Ayẹyẹ | Amì-ẹ̀yẹ | Ẹni tí ó gbàá | Èsì |
---|---|---|---|---|
2014 | City People Entertainment Awards | Best Supporting Actor | Ken Erics | Gbàá |
2014 | Afrifimo Awards (USA) | Best Lead Actor | Ken Erics | Gbàá |
2015 | Golden Icons Movie Awards (GIAMA) 2015 Awards | Best Actor in a Lead Role | Ken Erics | Wọ́n pèé |
Golden Icons Movie Awards (GIAMA) 2015 Awards | Best 'on-screen duo' | Ken Erics and Kiki Omeili | Wọ́n pèé | |
City People Entertainment Awards | Best Actor | Ken Erics | Gbàá | |
Afrifimo Awards (USA) | Best 'on-screen duo' | Ken Erics | Wọ́n pèé | |
2017 | City People Entertainment Awards | Best Actor | Ken Erics | Gbàá |
Nollywood Ambassadors Awards | Best Actor of the Year | Ken Erics | Gbàá | |
2018 | Golden Movie Awards (GMA) 2018 | Best Supporting Actor | Ken Erics | Wọ́n pèé |
2019 | South South Achievers Awards (SSA) 2019 | Male Actor of the Year | Ken Erics | Gbàá |
Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀
àtúnṣeMovie Roles
Year | Title | Role | Director | Notes |
---|---|---|---|---|
2002 | Holy Prostitute | Doctor | Chris Ubani | Cameo Role |
2006 | Silence of the gods | Onyegbula | Teco Benson | Home Video |
2007 | Eran and Erak | Oliver | Theodore Anyanji | Feature Film |
2010 | Evil intention | Santos | Ugezu j Ugezu | Feature Film |
2011 | Gold not Silver | Nwokolo | Tchidi Chikere | Feature Film |
2011 | A Better Tomorrow | Izu | Michael JaJa | Feature Film |
2011 | Days of Gloom | Izu | Michael JaJa | Feature Film featuring John Dumelo, Olu Jacobs and Chioma Chukwuka |
2012 | The Illiterate | Ugo | Silvester Madu | Feature Film |
2013 | Release me oh Lord | Osita | Ifeanyi Ogbonna | Feature Film |
2014 | Father Muonso | Father Elijah | Vincent De Anointed | Feature Film |
2014 | Burning Bridges | Louis | Okechukwu Oku | Feature Film |
2014 | Sugarcane | Azuka | Obinna Ukeze | Feature Film |
2015 | Trials of Igho | Igho | Chris Eneaji | Lead/Feature Film |
2015 | Echoes of Love | Prince | Ugezu j Ugezu | Feature Film |
2015 | Omalicham | Jeremiah | Ugezu j Ugezu | Feature Film |
2016 | Almost Perfect | Nonso | Desmond Elliot | Feature Film |
2016 | Within these walls | Francis | Uche Jombo | Feature Film |
2016 | Valerie | Joe | Taiwo Shittu | Feature Film |
2016 | The Vengeance | Jeff | Goodnews Erico Isika | Feature Film |
2016 | Okafor's Law | Chuks A.k.A Fox | Omoni Oboli | Feature Film featuring Blossom a Chukwujekwu, Richard Mofe Damijo , Omoni Oboli |
2017 | Crossed Path | Jesse | Frank Rajah Arase | Feature Film featuring Okawa Shaznay, Frank Artus & Emem Inwang |
2017 | What Lies Within[11] | Brian | Vanessa Nzediegwu | Feature Film with Michelle Dede, Tope Tedela, Kiki Omeili |
2017 | Omugwo | Raymond | Kunle Afolayan | Feature Film featuring Patience Ozokwo, Ayo Adesanya, Omowunmi Dada |
2017 | Body Language | Lancelot | Moses Inwang | Feature Film featuring Ramsey Nouah, Tana Adelana |
2017 | The Bridge | Augustine | Kunle Afolayan | Feature Film featuring Chidinma Ekile, Demola, Adedoyin, Zach Orji |
2017 | Fate Of Amanda | |||
2018 | You Are My Light | Samson | Vincent D Anointed | Feature Film produced by Ken Erics and featuring Yvonne Jegede, Ebele Okaro |
2019 | Love Melody | Obiora | Ability Tagbo | Feature Film produced by Ken Erics and featuring Rachael Okonkwo |
2019 | Ordinary Fellows[12] | Ekene | Lorenzo Menakaya and Ikenna Aniekwe | Feature Film featuring Wale Ojo, Chiwetalu Agu and Somadina Adinma |
Ipa rẹ̀ lórí eré orí amóhù-máwòrán
Year | Title | Role | Director | Notes |
---|---|---|---|---|
2005 | Webs | Livinus Otteh | TV Series | |
2015 | Growing Old | Chidi | Chris Eneaji | TV Series |
Stage Plays
Title | Role | Writer |
---|---|---|
Hopes of the Living Dead | Hacourt Whyte | Ola Rotimi |
Trials of Oba Ovoramnwen | Consular | Ola Rotimi |
Hangmen Also Die | R.I.P | Esiaba Irobi |
Childe International | Chief | Wole Soyinka |
Everyman | Everyman | Obotunde Ijimere |
Grip Am | Ise | Ola Rotimi |
Gold, Frankincense and Myrrh | Prof Ogun | Esiaba Irobi |
Àwọn orin rẹ̀
àtúnṣe- Inozikwa Omee (2018)
- Thank You Baba (2019)
- Mama (2019)
- Many Mysteries (2019)
- Sugarcane Baby (2019)
- Pretence (2019)
- Anom Gi N’aka (2019)
- Love is Life (2019)
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Favour, Ugochukwu (18 January 2013). "TONTOH DIKE, KEN ERICS, EDOCHIE STARS, THE ILLITERATE". Nigeria Films (Lagos, Nigeria). Archived from the original on 31 March 2016. https://web.archive.org/web/20160331141727/http://www.nigeriafilms.com/news/19723/16/tontoh-dike-ken-erics-edochie-stars-the-illiterate.html. Retrieved 7 June 2016.
- ↑ Ola, Erinfolami (28 February 2014). "Nollywood Celebrities Birthday". Naijagists (Lagos, Nigeria). http://naijagists.com/nollywood-celebrities-birthday-ken-erics-teco-benson-lilian-bach-a-year-older-today/. Retrieved 7 June 2016.
- ↑ Emedolibe, Ngozi (9 March 2016). "My childhood interesting, entertaining —Ken Erics". National Mirror Newspaper (Lagos, Nigeria). Archived from the original on 14 March 2016. https://web.archive.org/web/20160314143834/http://nationalmirroronline.net/new/my-childhood-interesting-entertaining-ken-erics/. Retrieved 7 June 2016.
- ↑ Bassey, Wisdom (12 January 2015). "Interview with Actor Ken Erics One of Nollywood's Emerging faces". Daily Mail Nigeria (Lagos, Nigeria). Archived from the original on 6 May 2017. https://web.archive.org/web/20170506081139/http://dailymail.com.ng/interview-with-ken-erics-one-of-nollywoods-emerging-faces/. Retrieved 7 June 2016.
- ↑ Izuzu, Chidumga (29 February 2016). "Ken Erics: 5 things you probably don't know about actor". The Pulse Ng. Lagos, Nigeria. Archived from the original on 13 October 2020. Retrieved 17 November 2020.
- ↑ Sean, Sean (24 November 2014). "Interview With Nollywood Ken Eric, One Of Nigeria's Movie Industry Emerging Faces". Daily Mail Nigeria. Lagos, Nigeria. Archived from the original on 2 February 2017. Retrieved 17 November 2020.
- ↑ Izuzu, Chidumga (29 February 2016). "Cell 2". Amymuses's Blog. Lagos, Nigeria.
- ↑ Izuronye, Ernesta (28 February 2016). "Nollywood Actor Ken Erics Has A Passion for Music (Photos)". Nollywood Community. Lagos, Nigeria.
- ↑ Lere, Success (23 June 2014). "List Of Winners at City People Entertainment Awards 2014". Gistmainia. Lagos, Nigeria.
- ↑ Lere, Mohammed (18 August 2015). "Nollywood: List of celebrities who win at the 2015 city People Award". Premium Times. Lagos, Nigeria.
- ↑ https://dailytimes.ng/entertainment/tope-tedela-produces-first-movie/
- ↑ "Wale Ojo, Somadina Adinma and Chiwetalu Agu star in “Ordinary Fellows,” new Nollywood movie produced by Lorenzo Menakaya » YNaija". YNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-08-07. Retrieved 2020-05-17.