Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 13 Oṣù Kínní
- 1898 – Émile Zola ṣe àtẹ̀jáde "J'accuse...!"'(àwòrán), nínú ìwéìròyìn ní Paris láti tú àṣírí Ẹjọ́ Dreyfus.
- 1972 - Ìfipágbàjọba ológun ṣẹlẹ̀ ní Ghánà.
- 1990 – L. Douglas Wilder di ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà àkọ́kọ́ tọ́ jẹ́ dídìbòyàn bíi gómìnà ní USA nígbà tó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ bíi gómìnà ìpínlẹ̀ Virginia.
- 2001 – Ìwàrìrì-ilẹ̀ ní El Salvador pa àwọn ènìyàn 800.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1859 – Kostis Palamas, akọewì ará Gríìsì (al. 1943)
- 1924 – Paul Feyerabend, amòye ará Austria (al. 1994)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1941 – James Joyce, olùkòwé ará Írẹ́lándì (ib. 1882)
- 2010 – Teddy Pendergrass, akọrin R&B ará Amẹ́ríkà (ib. 1950)
Ṣíṣàtúnṣe ojúewé yìí látọwọ́ àwọn oníṣe tuntun tàbí àwọn oníṣe aláìtíìforúkọsílẹ̀ jẹ́ tí tìpa lọ́wọ́lọ́wọ́. See the protection policy and protection log for more details. If you cannot edit this ojúewé and you wish to make a change, you can submit an edit request, discuss changes on the talk page, request unprotection, log in, or create an account. |