Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 14 Oṣù Kọkànlá
- 1969 – Eto Apollo: NASA segbera Apollo 12, iranloso alakoso eniyan keji lo si oju Oaupa.
- 2002 – Argentina lugbese lori $805 million to ye ko san fun Banki Agbaye.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1864 – Herbert Macaulay (foto), oloselu ara Naijiria (al. 1946)
- 1922 – Boutros Boutros-Ghali, Akowe-Agba AAO ara Egypti
- 1954 – Condoleezza Rice, diplomati ati Alakoso Okere Amerika 66k
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1831 – Georg Wilhelm Friedrich Hegel, amoye ara Jemani (ib. 1770)
- 1915 – Booker T. Washington, alakitiyan eto araalu ara Amerika (ib. 1856)
- 2016 – Gwen Ifill, oniroyin ara Amerika (ib. 1955)