Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 29 Oṣù Kàrún
Ọjọ́ 29 Oṣù Kàrún: Ọjọ́ Òṣèlú ní Nàìjíríà
- 1973 – Tom Bradley jẹ́ dídìbòyàn bíi aláwọ̀dúdú àkọ́kọ́ baálẹ̀ Los Angeles, California.
- 1990 – Iléaṣòfin Rọ́síà dídìbòyàn Boris Yeltsin bí Ààrẹ Rọ́síà Sófìẹ̀tì.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1917 – John F. Kennedy (fọ́tò), Ààrẹ 35k Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà (al. 1963)
- 1926 – Abdoulaye Wade, Ààrẹ ilẹ̀ Sẹ̀nẹ̀gàl
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1958 – Juan Ramón Jiménez, olùkọ̀wé ará Spéìn (ib. 1881)
- 2010 – Dennis Hopper, òṣeré ará Amẹ́ríkà (ib. 1936)