Rọ́síà
Rọ́síà (pìpè [ˈrʌʃə], Rọ́síà: Росси́я, Rossiya) tabi orile-ede Ìparapọ̀ Rọ́sìà[6] (Rọ́síà: Российская Федерация, pípè [rɐˈsʲijskəjə fʲɪdʲɪˈraʦəjə] ( listen)), je orileijoba ni apaariwa Eurasia. O je orile-ede olominira sistemu aare die alasepapo to ni ipinle ijoba 83. Rosia ni bode mo awon orile-ede wonyi (latiariwaiwoorun de guusuilaorun): Norway, Finland, Estonia, Latvia, Lithuania ati Poland (lati egbe Kaliningrad Oblast), Belarus, Ukraine, Georgia, Azerbaijan, Kazakhstan, Saina, Mongolia, ati North Korea. O tun ni bode omi mo Japan (lati egbe Okun-omi Okhotsk) ati Amerika (lati egbe Bering Strait).
Ìparapọ̀ Rọ́sìà Russian Federation Российская Федерация Rossiyskaya Federatsiya | |
---|---|
Orin ìyìn: Государственный гимн Российской Федерации (Russian) Gosudarstvenny gimn Rossiyskoy Federatsii (transliteration) State Anthem of the Russian Federation | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Moscow |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Russian official throughout the country; 27 others co-official in various regions |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn | Russians 79.8%, Tatars 3.8%, Ukrainians 2%, Bashkirs 1.2%, Chuvash 1.1%, Chechen 0.9%, Armenians 0.8%, other – 10.4% |
Orúkọ aráàlú | Russian |
Ìjọba | Federal semi-presidential democratic republic |
Vladimir Putin (Владимир Путин) | |
Mikhail Mishustin (Михаил Мишустин) | |
Valentina Matviyenko (Валенти́на Матвие́нко)(UR) | |
Vyacheslav Volodin (Вячеслав Володин) (UR) | |
Aṣòfin | Federal Assembly |
Federation Council | |
State Duma | |
Formation | |
862 | |
882 | |
1169 | |
1283 | |
1547 | |
1721 | |
7 November 1917 | |
10 December 1922 | |
26 December 1991 | |
Ìtóbi | |
• Total | 17,075,400 km2 (6,592,800 sq mi) (1st) |
• Omi (%) | 13[1] (including swamps) |
Alábùgbé | |
• 2010 estimate | 141,927,297[2] (9th) |
• 2021 census | 146,171,015 |
• Ìdìmọ́ra | 8.4/km2 (21.8/sq mi) (217th) |
GDP (PPP) | 2009 estimate |
• Total | $2.126 trillion[3] (8th) |
• Per capita | $15,039[3] (51st) |
GDP (nominal) | 2009 estimate |
• Total | $1.255 trillion[3] (11th) |
• Per capita | $8,874[3] (54th) |
HDI (2007) | ▲ 0.817[4] Error: Invalid HDI value · 71st |
Owóníná | Ruble (RUB) |
Ibi àkókò | UTC+2 to +12 |
• Ìgbà oru (DST) | UTC+3 to +13 |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | right |
Àmì tẹlifóònù | +7 |
Internet TLD | .ru (.su reserved), (.рф2 2009) |
|
Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Category:Russia |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Awon Itokasi
àtúnṣe- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedgen
- ↑ Federal State Statistics Service of Russia
- ↑ 3.0 3.1 3.2 3.3 "Russia". International Monetary Fund. Retrieved 2010-02-02.
- ↑ Human Development Report 2009. The United Nations. Retrieved 5 October 2009.
- ↑ (Rọ́síà) "Russia allowed to register Internet domains in Cyrillic". Interfax. Retrieved 2008-07-20.
- ↑ "The Constitution of the Russian Federation". (Article 1). Retrieved 25 June 2009.