Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 30 Oṣù Kàrún
- 1966 – Won fikupa Alakoso Agba orile-ede Kongo tele Evariste Kimba ati awon oloselu bi melo kan ni Kinshasa leyin ase latowo Aare Joseph Mobutu.
- 1967 – Agbègbè Apáìlàoòrùn Nàìjíríà pe ra won ni olominira gege bi Orile-ede Biafra, eyi lo fa ibere ogun abele ni Nàìjíríà.
- 1998 – Iminle to lagbara to 6.6 lori iwon Richter sele ni apa-ariwa Afghanistan, o fikupa 5,000 eniyan.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1814 – Mikhail Bakunin, alaifejoba ara Russia (al. 1876)
- 1908 – Hannes Alfvén, onimofisiksi ara Sweden (al. 1995)
- 1974 – Big L, akorin rap ara Amerika (al. 1999)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1778 – Voltaire, onimoye ati akowe ara Fransi (ib. 1694)
- 1960 – Boris Pasternak, akowe ara Russia, elebun Nobel (ib. 1890)
- 1964 – Oba Akinyele, Olubadan (ib. 1882)
Ṣíṣàtúnṣe ojúewé yìí látọwọ́ àwọn oníṣe tuntun tàbí àwọn oníṣe aláìtíìforúkọsílẹ̀ jẹ́ tí tìpa lọ́wọ́lọ́wọ́. See the protection policy and protection log for more details. If you cannot edit this ojúewé and you wish to make a change, you can submit an edit request, discuss changes on the talk page, request unprotection, log in, or create an account. |