Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 30 Oṣù Kẹ̀wá
- 1922 – Benito Mussolini di Alákóso Àgbà ilẹ̀ Itálíà.
- 1947 – Ìpinu Gbogbogbò lórí Owó-orí Ọjà àti Bùkátà (GATT), tó jẹ́ ìpilẹ̀sẹ̀ fún Àgbájọ Bùkátà Àgbáyé (WTO), jẹ́ dídásílẹ̀.
- 1974 – Ìjà ẹ̀sẹ́ Rumble in the Jungle láàrin Muhammad Ali àti George Foreman wáyé ní Kinshasa, Zaire.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1885 – Ezra Pound, akọewì ará Amẹ́ríkà (al. 1972)
- 1960 – Diego Maradona, agbábọ́ọ̀lù tẹ́lẹ̀ ará Argẹntínà
- 1970 – Nia Long (fọ́tò), ọ̀ṣeré ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1975 – Gustav Ludwig Hertz, aṣefísíksì ará Jẹ́mánì (ib. 1887)
- 2002 – Jam Master Jay, akọrin rap ará Amẹ́ríkà (Run DMC) (ib. 1965)
- 2009 – Claude Lévi-Strauss, onímọ̀ ẹ̀dá-èníyàn àti ẹ̀yà-ènìyàn ará Fransi (ib. 1908)