Zina Lynna Garrison (ojoibi November 16, 1963, ni Houston, Texas) je agba tennis to ti feyinti lati Orile-ede Amerika. O gba ipo keji ni idije awon obinrin enikan ni Wimbledon 1990, o si gba ife-eye Grand Slam awon adalu enimeji meta ati eso wura idije awon obinrin enimeji ni Olimpiki 1988.

Zina Garrison
Orílẹ̀-èdèUSA USA
IbùgbéHouston, Texas, U.S.
Ọjọ́ìbí16 Oṣù Kọkànlá 1963 (1963-11-16) (ọmọ ọdún 61)
Houston, Texas, U.S.
Ìga1.64 m (5 ft 4+12 in)
Ìgbà tódi oníwọ̀fà1982
Ìgbà tó fẹ̀yìntì1997
Ọwọ́ ìgbáyòRight-handed (one handed-backhand)
Ẹ̀bùn owó$4,590,816
Ẹnìkan
Iye ìdíje587–270
Iye ife-ẹ̀yẹ14
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 4 (November 20, 1989)
Grand Slam Singles results
Open AustrálíàSF (1983)
Open FránsìQF (1982)
WimbledonF (1990)
Open Amẹ́ríkàSF (1988, 1989)
Ẹniméjì
Iye ìdíje436–231
Iye ife-ẹ̀yẹ20
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 5 (May 23, 1988)
Grand Slam Doubles results
Open AustrálíàF (1987, 1992)
Open FránsìQF (1988, 1989, 1991, 1995)
WimbledonSF (1988, 1990, 1991, 1993)
Open Amẹ́ríkàSF (1985, 1991)
Àdàpọ̀ Ẹniméjì
Iye ife-ẹ̀yẹ3
Grand Slam Mixed Doubles results
Open AustrálíàW (1987)
Open FránsìSF (1989)
WimbledonW (1988, 1990)
Open Amẹ́ríkàSF (1987)
Last updated on: July 12, 2008.
Iye ẹ̀ṣọ́ Olympiki
Women's tennis
Adíje fún the USA USA
Wúrà 1988 Seoul Women's doubles
Bàbà 1988 Seoul Women's singles