Ìròyìn Oṣù Keje 2012
- Olùdájọ́ Alooma Mariam Mukhtar di obìnrin àkọ́kọ́ tó di Olùdájọ́ Àgbà ilẹ̀ Nàìjíríà.
- Nínú Tẹ́nìs, Serena Williams àti Roger Federer gba ife-ẹ̀yẹ Ìdíje Wimbledon 2012.
- CERN polongo àwárí eruku tuntun pẹ̀lú ìní tó jọ bósónì Higgs (àwòrán) lẹ́yìn àdánwò pẹ̀lú Ẹ̀rọ Ìmúsáré Hádrónì Gbàngbà.