Roger Federer (Pípè nì Jẹ́mánì: [ˈfeːdəʁɐ]) (ojoibi 8 August 1981) je agba tenis ara Switsalandi to di Ipo No. 1 ATP mu fun rekodu ose 237 nitelentele lati 2 February 2004 de 18 August 2008.[2] Federer ti di ipo kinni mu fun apapo ose 285, to fi ose kan din si rekodu ose 286 ti Pete Sampras ni. Titi di 28 May 2012, ohun lo wa ni Ipo No. 3 Lagbaye. Federer ti gba ife-eye Grand Slam enikan awon okunrin ni igba 16 to je rekodu. O je ikan ninu awon okunrin atayo to gba gbogbo Grand Slam ati ikan ninu awon eniyan meta (pelu Andre Agassi ati Rafael Nadal) to seyi lori papa itayo otooto meta (papa alamo, onikoriko, ati olojulile). Ohun nikan ni okunrin atayo ninu tenis titi doni to de idopin idije Grand Slam kookan ni emarun o kerejulo ati idopin ikookan awon Idije ATP Masters 1000 mesesan. Opo awon olutuwo ere-idaraya, olugbewo tenis, ati awon atayo lowo ati tele gba pe Federer ni atayo tenis to gbokikijulo.[3][4][5][6][7][8][9]

Roger Federer
Orílẹ̀-èdè Switzerland
IbùgbéWollerau, Switzerland and Dubai, United Arab Emirates[1]
Ọjọ́ìbí8 Oṣù Kẹjọ 1981 (1981-08-08) (ọmọ ọdún 43)
Basel, Switzerland
Ìga1.85 m (6 ft 1 in)
Ìgbà tódi oníwọ̀fà1998
Ọwọ́ ìgbáyòRight-handed (one-handed backhand)
Ẹ̀bùn owó$76,541,427
Ẹnìkan
Iye ìdíje885–200 (81.57% in ATP World Tour and Grand Slam main draw matches, and in Davis Cup)
Iye ife-ẹ̀yẹ77 (4th in the Open Era)
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 1 (2 February 2004)
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́No. 7 (11 November 2013)
Grand Slam Singles results
Open AustrálíàW (2004, 2006, 2007, 2010)
Open FránsìW (2009)
WimbledonW (2003, 2004, 2005, 2006, 2007, 2009, 2012)
Open Amẹ́ríkàW (2004, 2005, 2006, 2007, 2008)
Àwọn ìdíje míràn
Ìdíje ATPW (2003, 2004, 2006, 2007, 2010, 2011)
Ìdíje Òlímpíkì Silver medal (2012)
Ẹniméjì
Iye ìdíje120–80 (60% in ATP World Tour and Grand Slam main draw matches, and in Davis Cup)
Iye ife-ẹ̀yẹ8
Ipò rẹ̀ gígajùlọNo. 24 (9 June 2003)
Grand Slam Doubles results
Open Austrálíà3R (2003)
Open Fránsì1R (2000)
WimbledonQF (2000)
Open Amẹ́ríkà3R (2002)
Àwọn ìdíje Ẹniméjì míràn
Ìdíje Òlímpíkì Gold medal (Àdàkọ:OlympicEvent)
Àwọn Ìdíje Ẹgbẹ́ Agbáyò
Hopman CupW (2001)
Last updated on: 24 January 2013.
Iye ẹ̀ṣọ́ Olympiki
Adíje fún Switzerland Switzerland
Men's Tennis
Wúrà 2008 Beijing Doubles
Fàdákà 2012 London Singles



  1. "Credit Suisse – Roger Federer, a Basel Boy Forever". Sponsorship.credit-suisse.com. Archived from the original on 2013-05-30. Retrieved 2013-01-22. 
  2. "Profile: Roger Federer – The greatest ever". CNN. 6 July 2009. Archived from the original on 30 April 2011. https://web.archive.org/web/20110430102905/http://edition.cnn.com/2009/SPORT/07/04/roger.federer.profile.wimbledon/index.html. Retrieved 3 October 2009. 
  3. Richard Evans (24 June 2007). "Jack the Lad". The Observer (UK). http://observer.guardian.co.uk/sport/story/0,,2110101,00.html. Retrieved 15 February 2009. "Jack Kramer 'is ready to anoint Roger Federer as the best he has seen'." 
  4. "Federer the greatest ever — Lloyd". BBC Sport. 7 June 2009. http://news.bbc.co.uk/sport2/hi/tennis/8088191.stm. Retrieved 7 June 2009. 
  5. Jago, Richard (5 June 2009). "'Roger Federer is the greatest' says Pete Sampras after record broken". The Guardian. London. http://www.guardian.co.uk/sport/2009/jul/05/pete-sampras-roger-federer-wimbledon. Retrieved 9 November 2010. 
  6. Barnes, Simon (8 June 2009). "Roger Federer, greatest of all time, ensures statistics back up unrivalled artistry". The Times (UK). Archived from the original on 15 June 2020. https://web.archive.org/web/20200615062650/http://www.thetimes.co.uk/. Retrieved 9 June 2009. 
  7. "Top 10 Men's Tennis Players of All Time". Sports Illustrated. Archived from the original on 19 September 2010. https://web.archive.org/web/20100919002329/http://sportsillustrated.cnn.com/multimedia/photo_gallery/1009/top.ten.tennis/content.1.html. Retrieved 23 September 2010. 
  8. Federer the best of all time, says Agassi
  9. Federer the best of all time, says Ivan Lendl[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]